Orits Williki
Ìrísí
Orits Wiliki jẹ́ olórin ti orílẹ̀-èdè Naijiria, tó máá ń kọ orin reggae. Ó dí gbajúmọ̀ nígbà tí ó gbé orin kan jáde ní ọdún 1989, tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ Tribulation.[1]
Wiliki tún jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ Musical Copyright Society of Nigeria, èyí tó jẹ́ ẹgbẹ́ olórogún ti Copyright Society of Nigeria.[2]
Àtòjọ àwọ orin rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Tribulation. 1989. Polydor Records
- Conqueror. 1990. Polydor Records
- Wha Dis Wha Dat. 1991. Premier Music.[3]
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Umahi, Sunday (February 8, 1992). "I am not mocking Muslims". Weekend Concord (Lagos).
- ↑ "CMO Approval: How MCSN lost out". Daily Independent (Lagos). July 31, 2010. https://allafrica.com/stories/201008040440.html.
- ↑ "Orits Williki Koleman Revolutionaire* - Wha' Dis Wha' Dat". Discogs (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-06-20.