Osinachi Ohale
Ìrísí
Personal information | |||
---|---|---|---|
Orúkọ | Osinachi Marvis Ohale | ||
Ọjọ́ ìbí | 21 Oṣù Kejìlá 1991 | ||
Ibi ọjọ́ibí | Owerri, Imo State, Nigeria | ||
Ìga | 1.76 m | ||
Playing position | Defender | ||
Club information | |||
Current club | Deportivo Alavés Gloriosas | ||
Senior career* | |||
Years | Team | Apps† | (Gls)† |
2008–2009 | Rivers Angels | ||
2010–2014 | Delta Queens | ||
2014 | Houston Dash | 19 | (1) |
2015–2017 | Rivers Angels | ||
2017–2018 | Vittsjö GIK | 22 | (1) |
2018–2019 | Växjö DFF | 25 | (0) |
2019–2020 | CD Tacón | 15 | (2) |
2020 | A.S. Roma Women | 2 | (0) |
2021 | Madrid CFF | 16 | (2) |
2021– | Deportivo Alavés Gloriosas | 5 | (1) |
National team‡ | |||
Nigeria women's national football team | 26 | (1) | |
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only and correct as of 19:33, 13 October 2021 (UTC) **Source: Houston Dash. † Appearances (Goals). |
Osinachi Ohale jẹ agbabọọlu lobinrin órilẹ ede naigiria ti a bini 21, óṣu December ni ọdun 1991. Elere naa ṣère fun Spanish Primera Division Club Deportivo Alaves ati apapọ team awọn obinrin ti órilẹ ede naigiria[1][2].
Àṣeyọri
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Osinachi kopa ninu ere idije awọn obinrin ilẹ Afirica nibi ti o jẹ àṣoju orilẹ ede naigiria ni ọdun 2010, 2014, 2016 ati 2018. Elere naa tun kopa ninu Cup FIFA awọn obinrin agabaye to waye ni ọdun 2011, 2015 ati 2019[3].