Osita Osadebe
Ìrísí
Chief Stephen Osita Osadebe | |
---|---|
Fáìlì:Chief Osadebe.jpg | |
Background information | |
Orúkọ àbísọ | Stephen Osita Osadebe |
Wọ́n tún mọ̀ọ́ bíi | Osadebe, The Doctor of Hypertension |
Ọjọ́ìbí | Atani, Colony of Nigeria | 17 Oṣù Kẹta 1936
Ìbẹ̀rẹ̀ | Atani, Nigeria |
Aláìsí | 11 May 2007 St. Mary's Hospital Waterbury, Connecticut, United States | (ọmọ ọdún 71)
Irú orin | Igbo Highlife |
Occupation(s) | singer, songwriter, record producer |
Years active | 1958–2007 |
Labels | Polygram Records Nigeria |
Associated acts | The Empire Rhythm Orchestra, Prince Nico Mbarga, Rex Lawson, Celestine Ukwu, Eddie Okonta, Victor Olaiya, Fred Coker, Victor Uwaifo |
Website | Chief Osita at Calabash music |
Chief Stephen Osita Osadebe /θj/(tí wọ́n bí ní March 17, 1936[1] tó sì ṣaláìsí ní May 11, 2007),[2] tí ọ̀pọ̀ ènìuàn mọ̀ sí Osita Osadebe, jẹ́ olórin, tó wá láti Atani. Ọ̀kan lára àwọn orin rẹ̀ tó gbajúgbajà tó kọ ní ọdún 1984 tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ "Osondi Owendi", èyí tó fi ẹsẹ̀ rẹ̀ múlẹ̀ gẹ́gẹ́ bí olórin tó gbajúmọ̀ ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ó sì jẹ́ ọ̀kan lára àwọn orin oeílẹ̀-èdè yìí tó gbajúmọ̀ jù lọ.[3]
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Àdàkọ:Cite AV media notes
- ↑ "Chief Stephen Osita Osadebe Passes Away On May 11, 2007". Global Rhythm Magazine News. May 15, 2007. Archived from the original on January 29, 2013. Retrieved April 5, 2010. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Nigeria's Chief Stephen Osita Osadebe dead". United Press International. May 19, 2007. Retrieved 2010-04-05.