Jump to content

Osmania University

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Àdàkọ:Use Indian English

Osmania University
Fáìlì:Osmania University Logo.png
Motto in EnglishLead us from Darkness to Light
Established1918; ọdún 106 sẹ́yìn (1918)
TypePublic
ChancellorGovernor of Telangana
Vice-ChancellorM. Dana Kishore, IAS
Academic staff445[1]
Students10,280[1]
Undergraduates1,989[1]
Postgraduates5,091[1]
Doctoral students3,200[1]
LocationTarnaka, Secunderabad, Hyderabad, Telangana, India
CampusUrban
Websiteosmania.ac.in

Fáfitì Osmania jẹ́ ilé-ẹ̀kọ́ gíga ti ìjọba Ìpínlẹ̀ tí ó ní oríṣiríṣi kọ́lẹ́ẹ̀jì nínú tó kalẹ̀ sí Hyderabad, Telangana, ní orílẹ̀-èdè India. Mir Osman Ali Khan, tí ó jẹ́ Nizam keje titi Hyderabad, dá sí pípè firman fún dídá sílẹ̀ rẹ̀ ní ọjọ́ kọkàndínlọ́gbọ̀n oṣù kẹjọ ọdún 1917.[2] Ohun ní ilé-ẹ̀kọ́ kẹ̀ta tó ti pẹ́ ní apá Gúúsù ilẹ̀ Indian, ó jẹ́ àkọ́kọ́ tí àkọ́kọ́ dá sílẹ̀ lábẹ́ ìjọba Hyderabad ti àná.[3][4][5]Ohun ní ilé-ẹ̀kọ́ àkọ́kọ́ ní ilẹ̀ India tí ó ma kọ́kọ́ lo èdè Urdu fi ṣe ìlànà èdè, ní tòótọ́ o, èdè Gẹ̀ẹ́sì náà pọn dandan gẹ́gẹ́ bí iṣẹ́.

Osmania jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ilé-ẹ̀kọ́ tó tóbi jù ní àgbáyé, pẹ̀lú ẹgbẹ̀rún lọ́nà àádọ́rùn-ún akẹ́kọ̀ọ́ ní ọgbà ilé-ẹ̀kọ́ náà, àti àwọn tókù tó so mọ.Kọ́lẹ́ẹ̀jì ilé ogun Osmania náà jẹ́ èyí tó jẹ́ ètò tí wọ́n ń ṣe ní ilé-ẹ̀kọ́ Osmania tó ti so mọ tẹ́lẹ̀ rí, ṣùgbọ́n ní báyìí, ó ti wà lábẹ́ ilé-ẹ̀kọ́ gíga Kaloji Nayarana Rao fún ètò ìlera Sáyẹ́ǹsì.

Students dressed in sherwani at the University College of Arts, c. 1939–1945.
B. E. Vijayam addresses students with the arts college in the background, c. 1973.

Ní 1917, Ọ̀gbẹ́ni Akbar H Ker tẹnu mọ́ ìwúlò fún dídá ilé-ẹ̀kọ́ gíga Hyderabad kalẹ̀, pẹ̀lú lílo èdè Urdu fún ìlànà ètò ẹ̀kọ́ wọn, gẹ́gẹ́ bí èdè tó gbajúgbajà jù ní orílẹ̀-èdè Indian.[6] Ní ọjọ́ kẹrìndínlógún oṣù kẹrin ọdún 1917,Nizam titi Hyderabad Mir Osman Al Khan lo fireman láti fi dá ilé-ẹ̀kọ́ gíga Osmania sílẹ̀.

Ilé-ẹ̀kọ́ gíga náà bẹ̀rẹ̀ ní ọdún 1918 ní ilé kan tó sún mọ́ Kọ́lẹ́ẹ̀gì Nizam ní Basheerbagh.

[7] Agbo ẹ̀ka ẹ̀kọ́ méjì péré ni ó kọ́kọ́ wà níbẹ̀, agbo ẹ̀ka ẹ̀kọ́ iṣẹ́ ọnà àti ẹ̀ka ẹ̀kọ́ nípa ẹ̀sìn. Àwọn ọ̀wọ́ tí akẹ́kọ̀ọ́ tí wọ́n sì kọ́kọ́ gbà wọlé jẹ́, okòólénígba lé márùn-ún àti àwọn ọmọ ẹgbẹ́ agbo ẹ̀ka ẹ̀kọ́ márùndínlọ́gbọ̀n.[8]

ÀWỌN ìjọba pe Patrick Geddes àti Jasper kí wọ́n dá ọgbà títí láé láé sí Fáfitì náà.[9] Geddes ṣe àṣeyọrí nípa ìwádìí ilẹ̀ yìí, tí ó sì ṣe àgbékalẹ̀ èsì rẹ̀ ní ọdún1923.[10] Jasper ya àwòrán ọ̀nà tí wọ́n a gbà kọ́ ilé náà tí Nizam si bẹ̀rẹ̀ ìpìlẹ̀ ọgbà náà ní ọjọ́ kaàrún oṣù keje ọdún 1934.[10] Lẹ́yìn tí Jasper kúrò ní Hyderabad, ayàwòrán ilẹ̀ ti ìjọba, Zain Yar Jung ṣe àbójútó kíkọ́ ọgbà ilé ẹ̀kọ́ náà.

Lẹ́yìn Ìgbòmìnira (1947 sí àkókò tí a wà yìí)

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Lẹ́yìn Ìgbòmìnira àti wíwọlé

The Nizam Mirnísọdún man AlFáfiiì náà bọ́ sábẹ́ wíwò ìjọba Ìpínlẹ̀. Lẹ́yìn ìdìbò àkọ́kọ́ fún ìjọba Ìpínlẹ̀ ìjọba àárín gbùnǹgbun kéde èrò rẹ̀ pé kí àwọn sọ Fáfitì Osmania di Fáfitì àárín gbùnǹgbun pẹ̀lú fífi èdè Hindi fi ṣe ìlànà wọn. Ṣùgbọ́n èyí ṣe okùnfà ìfẹ̀hónúhàn, ṣùgbọ́n wọ́n fi èrò náà sílẹ̀ lẹ́yìn ìkọ́kàn sókè tó rú sókè láti ọ̀dọ̀ àwọn

[11]

heNí ìgbẹ̀yìn, èdè Gẹ̀ẹ́sì padà rọ́pò Urdu ni fún ìlànà wọn, wọ́n sì yọ adé Nizam kúrò nínú asíwájú ilé-ẹ̀kọ́ gíga náà.

69
The University College of Arts and Social Sciences has an architectural heritage structure similar to College of Sultan Hassan in Cairo, Egypt.[12]

The Main campus is a chief intellectual centre in Hyderabad, and its alumni and faculty members include many distinguished individuals, including former Prime Minister of India P. V. Narasimha Rao. Admission to Main campus departments of Genetics, Biochemistry, Biotechnology, Chemistry, Engineering, Management, and Law is highly competitive.[13] The state government has appointed Prof S.Ramachandram as vice chancellor of the university. The university is accredited by the NAAC with an 'A+' Grade and conferred with the status of 'University with Potential for Excellence' by the UGC, New Delhi.[14]

The University Colleges are located in begumpet university. There are ten such colleges: the University College of Arts and Social Sciences, University College of Commerce & Business Management, University College of Technology, University College of Engineering, University College of Law, University College of Science, Institute of Advance Study in Education, and PG College of Physical Education. The university offers courses in Humanities, Arts, Sciences, Social Sciences, Law, Engineering, Medicine, Technology, Commerce and Business Management, Information Technology and Oriental Languages. In 2001, Osmania was awarded five-star status by the National Accreditation and Assessment Council (NAAC) of the University Grants Commission, part of the Government of India.[15]

The university has a campus of nearly 1600 acres (6 km2) with 300,000 students (counting all the campuses, constituent affiliated colleges and district centres) making it one of the largest higher education systems in India. Nearly 5000 faculty and staff are employed at Osmania.[16] It attracts students from across the nation as well as from other countries.[17]

Organisation and administration

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
The College of Engineering was one of the top 15 engineering schools in the country in 2012[18][19]

Constituent colleges

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Osmania University is a confederation of university colleges, constituent colleges, and affiliated colleges. The constituent colleges of the university include:[20]

Other Autonomous Centers

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Affiliated engineering colleges

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

The affiliated engineering colleges of the university are mostly scattered throughout the GHMC area and offer various undergraduate and post-graduate engineering courses.[21] The affiliated engineering colleges include (in no particular order):

Chaitanya Bharathi Institute of Technology is affiliated to the Osmania University
The College of Law is one of the top 15 law schools in the country[22]

Osmania is a non-profit university which is funded and managed by the government. Admissions into the Bachelor of Engineering, Masters and Doctoral programs in main campus is on a merit basis, evaluated by national entrance examinations (EAMCET, GATE, BCFSBTGMES-N&D, TSLAWCET, O.U. PhD Entrance Exam, DOST etc.) for each of the courses offered.

Fáìlì:OsmaniaUniv Library.jpg
The University Library

The University Library is the main library of the university and it was founded in 1918 along with the university. It has close to 500,000 books and more than 6000 manuscripts, which includes rare palm leave manuscripts. It also has various journals, government documents, etc. The main library coordinates a library system, which connects the libraries in the entire campus and other constituent college libraries.[23][24][25]

Àdàkọ:Infobox India university ranking Osmania University has ranked 1201–1400 in the world and 401–450 among universities in Asia category by the by the QS World University Rankings of 2023.[26][27] The Times Higher Education World University Rankings ranked it 1201–1500 globally in the 2023 ranking[28] 301–350 in Asia in 2022[29] and 301–350 among Emerging Economies University Rankings 2021.[30]

In India, the National Institutional Ranking Framework (NIRF) ranked Osmania University 43rd among Indian universities and 70th overall in 2024.[31][32]

The research activities are funded by various autonomous agencies of the government of India. Foreign students are also admitted to the university via UFRO (University Foreign Relations Office) that allots admissions with minimum criteria. Indian students living overseas Non-resident Indian are also admitted through UFRO that are usually ineligible to get admissions via the entrance exams quota.

Notable alumni and faculty

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Notable alumni of Osmania University include 9th Prime Minister of India P. V. Narasimha Rao,[13] Jaipal Reddy, cabinet minister, 16th and last Chief Minister of united Andhra Pradesh with Telangana Nallari Kiran Kumar Reddy, CEO Adobe systems Shantanu Narayen and senior advocate Subodh Markandeya.

Other alumni include spiritual guide and founder of Shrimad Rajchandra Mission Dharampur, Pujya Gurudevshri Rakeshji,[33] pro chancellor of khaja bandanawaz university Syed Muhammad Ali Al Hussaini, former Indian Cricket team captain Mohammed Azharuddin, cricket commentator Harsha Bhogle, novelist Venkatesh Kulkarni, author and poet Sneha Narayanan, PDSU founder George Reddy, former Union Home Minister Shivraj Patil, former governor of the Reserve Bank of India Yaga Venugopal Reddy, chemist Garikapati Narahari Sastry, Metallurgist and former Vice Chancellor of Banaras Hindu University Patcha Ramachandra Rao and physicist Raziuddin Siddiqui. Rakesh Sharma, cosmonaut and the first Indian to travel in space, was a graduate of Osmania.[34] Karan Bilimoria, founder of Cobra Beer, Member of the House of Lords, and the seventh Chancellor of the University of Birmingham earned his Bachelor of Commerce degree from Osmania in 1981.[35] Rafi Ahmed, a well-known virologist and immunologist graduated from Osmania University in 1968.

Notable former faculty members of the university include Bhadriraju Krishnamurti, Dravidianist and linguist, and founder of linguistics department at the university, physicist Suri Bhagavantam, and linguist Masud Husain Khan.[citation needed]

  1. 1.0 1.1 1.2 1.3 1.4 "NIRF 2022" (PDF). Osmania University. Archived from the original (PDF) on 10 July 2022. Retrieved 10 July 2022.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  2. Roger L. Geiger (2009). Curriculum, accreditation, and coming of age of higher education. Transaction Publishers. pp. 154–155. ISBN 978-1-4128-1031-9. https://books.google.com/books?id=Mc4gszrwUBQC&q=formation+osmania+university&pg=PA154. Retrieved 16 October 2011. 
  3. "H.E.H. Nizam Mir Osman Ali Khan". http://www.osmania.ac.in/InfoAct/Item01.pdf. 
  4. History Archived 22 February 2008 at the Wayback Machine. oucde.ac.in
  5. "INSA". Insaindia.org. http://insaindia.org/detail.php?id=n93-1132. 
  6. Akbar, Syed (23 April 2017). "OU architect was Nizam's emissary before merger". The Times of India (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 5 November 2019. Retrieved 6 October 2019.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  7. "Osmania University first varsity in India to introduce Urdu medium". The Times of India. 2017-02-22. ISSN 0971-8257. https://timesofindia.indiatimes.com/city/hyderabad/osmania-university-first-varsity-in-india-to-introduce-urdu-medium/articleshow/57283475.cms. 
  8. Mohan, Saadhya (2022-05-06). "In Limelight for Denying Entry to Rahul, Osmania University Has a Rich History". TheQuint (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-06-11. 
  9. "Arts College building, a hand-me-down architectural gem" (in en-IN). The Hindu. 2017-04-08. ISSN 0971-751X. https://www.thehindu.com/news/cities/Hyderabad/arts-college-building-a-hand-me-down-architectural-gem/article17895207.ece. 
  10. 10.0 10.1 "How the Osmania University came about" (in en-IN). The Hindu. 2019-01-28. ISSN 0971-751X. https://www.thehindu.com/news/cities/Hyderabad/how-the-osmania-university-came-about/article26112585.ece. 
  11. "Dispute over logo at Hyderabad's Osmania University". Deccan Chronicle (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 22 January 2017. Archived from the original on 9 October 2019. Retrieved 9 October 2019.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  12. "A slice of Egypt in Hyderabad". The Hindu (Chennai, India). 14 February 2011. http://www.hindu.com/2011/02/14/stories/2011021462500400.htm. 
  13. 13.0 13.1 "P. V. Narasimha Rao – A Profile". Indian PM's official website. Archived from the original on 28 March 2009.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  14. "Osmania University ranked 6th among top ten universities". http://www.osmania.ac.in/Pressnote-OU6thRanking.pdf. 
  15. Team indiaresultszone.com (25 November 2007). "Ranking of University | India". Indiaresultszone.com. Archived from the original on 5 June 2012. https://web.archive.org/web/20120605010942/http://indiaresultszone.com/ranking.html. 
  16. "About Osmania University". Osmania University. Archived from the original on 4 October 2013. Retrieved 3 October 2013.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  17. Aarti Dhar (15 July 2012). "News / National : Still a small global campus". The Hindu (Chennai, India). http://www.thehindu.com/news/national/article3640561.ece. 
  18. "Overall Ranking of Top Engineering Colleges". http://ghrdc.org/pdfs/overall_results11.pdf. 
  19. Special Correspondent (23 July 2012). "Cities / Hyderabad : Osmania University computer science students placed high". The Hindu (Chennai, India). http://www.thehindu.com/news/cities/Hyderabad/article3672257.ece. 
  20. "Osmania University Constituent Colleges". osmania.ac.in. Archived from the original on 26 December 2018. Retrieved 29 June 2019.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  21. "Affiliated Colleges List Under Osmania University". Osmaina University. Archived from the original on 15 September 2013. Retrieved 1 October 2013.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  22. "Outlook Rankings: NALSAR, Hyderabad ranked the best law school in the country; followed by NLSIU, Bangalore and NLIU, Bhopal". Barandbench.com. http://barandbench.com/brief/2/2512/outlook-rankings-nalsar-hyderabad-ranked-the-best-law-school-in-the-country-followed-by-nlsiu-bangalore-and-nliu-bhopal. 
  23. "University Library". Osmania University. Archived from the original on 5 October 2013. Retrieved 3 October 2013.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  24. Parasa, Rajeswari (18 May 2019). "Osmania University renames library after Dr B R Ambedkar". Deccan Chronicle (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 6 June 2019. Retrieved 14 September 2019.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  25. Ramu, Marri (6 June 2019). "PIL against changing name of Osmania varsity library" (in en-IN). The Hindu. ISSN 0971-751X. https://www.thehindu.com/news/national/telangana/pil-against-changing-name-of-osmania-varsity-library/article27527857.ece. 
  26. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named Rankings_QS_W_2023
  27. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named Rankings_QS_A_2023
  28. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named Rankings_THE_W_2023
  29. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named Rankings_THES_A_2022
  30. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named Rankings_THES_E_2022
  31. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named Rankings_NIRF_U_2024
  32. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named Rankings_NIRF_O_2024
  33. "Gurudev Rakesh Bhai". Spiritual Science Museum. Puremindz. Archived from the original on 16 March 2022. Retrieved 21 July 2022.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  34. "Nizam College fete from tomorrow". The Hindu. 19 February 2008. Archived from the original on 4 March 2008. https://web.archive.org/web/20080304010048/http://www.hindu.com/2008/02/19/stories/2008021958240200.htm. 
  35. "Lord Bilimoria appointed as Chancellor of the University of Birmingham". Birmingham University. Retrieved 17 December 2014. 

Àdàkọ:Universities in Telangana Àdàkọ:Hyderabad topics

Àdàkọ:Authority control