Jump to content

Otosirieze Obi-Young

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Otosirieze Obi-Young
Ọjọ́ìbí1994 (ọmọ ọdún 29–30)
Aba, Ìpínlẹ̀ Abia, Nàìjíríà
Iléẹ̀kọ́ gígaYunifásitì ti Nàìjíríà, Nsukka
Iṣẹ́
  • Writer
  • Editor
  • Journalist
  • Curator
Organization
  • Folio Nigeria
  • Open Country Mag
Websitehttps://otosirieze.com/

Otosirieze Obi-Young (tí a bí ní ọdún 1994) jé òǹkọ̀wé ọmọ orílẹ̀-èdè Naijiria, olóòtú àti akọ̀ròyìn. Ó jẹ́ olóòtú àgbà fún Open Country Mag, èyí tó jẹ́ ìwé-ìròyìn tó sọ nípa ilẹ̀ Africa, àti àwọ lítíréṣọ̀ rẹ̀.[1] Ó jẹ́ olóòtú ti Folio Nigeria, èyí tó jẹ́ apá kan CNN, tó ń sọ̀rọ̀ nípa iṣẹ́-ọnà orílẹ̀-èdè Naijiria, ìdókòwò rẹ̀ àti eré-ìdárayá rẹ̀.[2] Ó jẹ́ igbákejì olóòtú ti ìwé-ìròyìn orí ẹ̀rọ-ayélujára Brittle Paper. [3][4] Ní ọdún 2019, ó jáwé olúborí, ó sì gba àmì-ẹ̀yẹ The Future Awards Africa fún lítírẹ́ṣọ̀.[5][6][7]

Àwọn iṣẹ́ rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àwọn ìtàn kúkurú

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  • A Tenderer Blessing. 
  • Mulumba. 
  • Pride and Prejudice: African Perspectives on Gender, Social Justice and Sexuality. 

Àkọsílẹ̀ rẹ̀ lórí àṣà

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  • "Chimamanda Ngozi Adichie Is in a Different Place Now", Open Country Magazine, 2021 [8]
  • "How Teju Cole Opened a New Path in African Literature", Open Country Magazine, 2021[9]
  • "Cameroon's New Literary Generation Comes of Age, as Anglophone Crisis Deepens", Open Country Magazine, 2021[10]
  • "With Novels and Images, Maaza Mengiste Is Reframing Ethiopian History", Open Country Magazine, 2021[11]
  • "The Making of Ndebe, an Indigenous Script for the Igbo Language", Folio Nigeria, 2020
  • "In the Age of Afrobeats, a New Sound for Highlife", Folio Nigeria, 2020
  • "In Nigeria, Investigative Journalism Finds Culture Impact", Folio Nigeria, 2020

Àtòjọ àwọn àmì-ẹ̀yẹ rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  • 2019: The Future Awards Africa Prize for Literature
  • 2020: The 100 Most Influential Young Nigerians, by Avance Media.[12]

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. Obi-Young, Otosirieze (17 September 2021). "Chimamanda Ngozi Adichie Is on the September 2021 Cover of Open Country Mag". Open Country Mag. Retrieved 4 May 2022. 
  2. Clement, Phillips (18 May 2020). "Folio Group appoints Otosirieze Obi-Young as editor". https://dailytimes.ng/folio-group-appoints-obi-young-as-writer-editor/. 
  3. Bedingfield, William (9 April 2018). "Eight Nigerian authors discuss Nigeria's literary culture". Dazed Digital. Retrieved December 25, 2018. 
  4. "Otosirieze : Statement on Leaving Brittle Paper". Otosirieze (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-04-15. Retrieved 26 April 2020. 
  5. "Burna Boy, Israel Adesanya, Timini Egbuson, Simi 'Drey' Adejumo, Tolani Alli, others emerge winners at The Future Awards Africa 2019". The Future Awards Africa. 26 November 2019. https://awards.thefutureafrica.com/burna-boy-israel-adesanya-timini-egbuson-simi-drey-adejumo-tolani-alli-others-emerge-winners-at-the-future-awards-africa-2019/. Retrieved 22 January 2020. 
  6. "Burna Boy, Tolani Alli, Isaac Success … Meet the Winners at The Future Awards Africa 2019!". Bella Naija. 25 November 2019. Retrieved 26 November 2019. 
  7. Ibeh, Chukwuebuka (November 24, 2019). "Otosirieze Obi-Young Wins Inaugural The Future Awards Prize for Literature". https://brittlepaper.com/2019/11/otosirieze-obi-young-wins-inaugural-the-future-awards-africa-prize-for-literature/. 
  8. Obi-Young, Otosirieze (2021-09-20). "Cover Story: Chimamanda Ngozi Adichie on Half of a Yellow Sun at 15, Her Private Losses, and Public Evolution". Open Country Mag (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-11-09. 
  9. Obi-Young, Otosirieze (2021-07-04). "Cover Story: How Teju Cole Opened a New Path in African Literature". Open Country Mag (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-11-09. 
  10. Obi-Young, Otosirieze (2021-06-25). "In Cameroonian Literature, a New Generation Comes of Age". Open Country Mag (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-11-09. 
  11. Obi-Young, Otosirieze (2021-01-16). "Maaza Mengiste's Chronicles of Ethiopia". Open Country Mag (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-11-09. 
  12. "Profiles: 2019 100 Most Influential Young Nigerians". Avance Media. Retrieved 19 August 2020.