Our People's FM
City | Fajuyi, Ado-Ekiti, Ekiti State, Nigeria |
---|---|
Frequency | (104.1 MHz) |
Website | ourpeoplesfm1041.com.ng/ |
Our People's FM (104.1 MHz) jẹ́ ilé-iṣẹ́ ìgbóhùnsáfẹ́fẹ́ Naijiria tí ó wà ní agbègbè Fajuyi ní Ado-Ekiti, Èkìtì.
Ìtàn
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ní ọjọ́ kẹrìnlá oṣù kejì ọdún 2019, àwọn ọlọ́pàá àtakò ìpaniláyà ti ìpínlẹ̀ wọ ibùdó náà tí wọ́n sì fi tipatipa tìí fún ìgbà kan. Ìdí tí wọ́n múlẹ̀ fún ìtìpa náà ni pé ilẹ̀ tí ilé-iṣẹ́ ìgbóhùnsáfẹ́fẹ́ wà lórí rẹ̀ ti lòdì sí àwọn ìlànà ìdàgbàsókè ilẹ̀ ti ìlú nítorí kò ní ètò tí a fọwọ́sí fún gbígbé ilé ètò afẹ́fẹ́.[1][2] Àmọ́, wọ́n ní ìtìpa náà nííṣe pẹ̀lú ọ̀rọ̀ ìṣèlú, nítorí wọ́n sọ pé ilé-iṣẹ́ náà ni Gómìnà tẹ́lẹ̀, Ayodele Fayose, tó sọ wípé ìtìpa náà jẹ́ ọ̀nà àbáyọ fún jìbìtì ìbò àbẹ́lé nínú ẹgbẹ́ òṣèlú All Progressives Congress.[3] Ilé náà àti àwọn ohun-ìní mìíràn ti Fayose ni Ìgbìmọ̀ Ẹ̀ṣẹ̀ Ìṣòwò àti Owó ti fi èdìdì tì tẹ́lẹ̀. [4]
Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Ogunje, Victor (2019-02-14). "Ekiti Seals off Radio Station Allegedly Owned by Fayose". THISDAYLIVE (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-12-08.
- ↑ "Ekiti govt seals radio station allegedly owned by Fayose". Champion Newspapers LTD (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-02-14. Archived from the original on 2021-12-08. Retrieved 2021-12-08.
- ↑ Afolabi, Ayodele (2019-02-15). "Ekiti seals radio station for allegedly flouting building laws". The Guardian (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2021-12-08. Retrieved 2021-12-08.
- ↑ Nwaoko, Sam (22 November 2018). "PHOTOS: EFCC storms Ekiti, seals 13 properties allegedly linked to Fayose". https://tribuneonlineng.com/photos-efcc-seals-off-alleged-fayoses-properties-in-ekiti/.