Jump to content

Oyeniyi Abejoye

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Oyeniyi Abejoye
Òrọ̀ ẹni
Ọmọorílẹ̀-èdèNigerian
Ọjọ́ìbí16 Oṣù Kínní 1994 (1994-01-16) (ọmọ ọdún 32)
Lagos, Nigeria
Sport
Erẹ́ìdárayáTrack and field
Event(s)100 metres, 110 metres hurdles
Achievements and titles
Personal best(s)100 m – 10.61 (2019)
200 m – 21.89 (2017)
110 mH – 13.67 (2019)[1]

Oyeniyi Abejoye (A bi ni ojo kerindilogun Osu kinni odun 1994) jẹ́ eleré ìdárayá àti pápá orílẹ̀-èdè Nàìjíríà kàn ti o ṣe amọja nínú àwọn idiwọ mítà 110 ati pe o tun díje bi asare.[2] O dije ni Awọn ere àgbáyé 2018 ni idiwọ mita 110.[3] Ni Awọn ere Áfíríkà 2019, o dije nínú idiwọ mita 110, o gba ami-ẹri fadaka kan.[4][5] Ó jẹ́ ikan ninu àwọn ọmọ orílẹ̀- èdè Nàìjíríà tí wọ́n gba àmì ẹ̀yẹ fàdákà nínú àwọn eré ìdárayá ilẹ̀ Áfíríkà ti ọdún 2019.[6] O gba àmì ẹ̀yẹ fàdákà 110-mita ìdíwọ̀ ni 2018 Idije elere ìdárayá Afirika ni ìlú Asaba.[7]

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named "iaaf".
  2. ↑ "Nigeria’s Fastest Hurdler, Oyeniyi Abejoye Headlines 1st Athletics In Schools Program". nigeriaathletics.com. Retrieved 27 September 2018.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
  3. ↑ "Oyeniyi Abejoye". results.gc2018.com. Retrieved 15 April 2018.
  4. ↑ "African Games (Athletics) Results - Men's 4x100m Relay Final". 2019 AG official website. Archived from the original on 28 August 2019. Retrieved 28 August 2019. Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  5. ↑ "2019 African Games – Athletics – Results Book" (PDF). Archived from the original (PDF) on 1 September 2019. Retrieved 7 September 2019. Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  6. ↑ "African Games (Athletics) Results - Men's 110m Hurdles Final". 2019 AG official website. Archived from the original on 27 August 2019. Retrieved 27 August 2019. Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  7. ↑ "Asaab 2018: Abejoye Oyeniyi clinches silver in 110m hurdles". Voice of Nigeria. https://www.von.gov.ng/asaab-2018-abejoye-oyeniyi-clinches-silver-in-110m-hurdles/.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]