Oyinyechi Zogg
Ìrísí
Personal information | |||
---|---|---|---|
Orúkọ | Onyinyechi Salome Zogg[1] | ||
Ọjọ́ ìbí | 3 Oṣù Kẹta 1997[2] | ||
Ibi ọjọ́ibí | Bern, Switzerland | ||
Ìga | 1.72 m[2] | ||
Playing position | Defender[2] | ||
Senior career* | |||
Years | Team | Apps† | (Gls)† |
Young Boys | 16 | (1) | |
Femina Kickers Worb | |||
FC Bethlehem | |||
2019–2021 | Zürich | 35 | (4) |
2021–2022 | ASJ Soyaux | 11 | (0) |
2022–2023 | Turbine Potsdam | 3 | (0) |
National team‡ | |||
2021– | Nigeria | 2 | (0) |
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only and correct as of 7 May 2023. † Appearances (Goals). |
Onyinyechi Salome Zogg (tí wọ́n bí ní 3 March 1997) jẹ́ agbábọ́ọ̀lù tó ń gbá bọ́ọ̀lù nípò alátakò. Ìlú Switzerland ni wọ́n bí i sí, ó sì ṣojú orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ní ìdíje gbogboogbò.
Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Wọ́n bí Zogg sí ìlú Bern.[4] Bàbá rẹ̀ jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Switzerland, ìyá rẹ̀ sì jẹ́ ọmọ Nàìjíríà.
Iṣẹ́ rẹ̀ ní ilé-ẹ̀kọ́
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ilé-ìwé Monroe College ni Zogg lọ, ní United States.[4]
Iṣẹ́ rẹ̀ ní ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Zogg gbá bọ́ọ̀lù fún ẹgbẹ́ BSC Young Boys, Femina Kickers Worb, FC Bethlehem àti Zürich ní Switzerland.
Iṣẹ́ rẹ̀ káàkiri àgbááyé
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Zogg ṣe àfihàn ẹlẹ́ẹ̀kejì fún Nàìjíríà ní 10 June 2021 ní ayò ọlọ́rẹ̀ẹ́jọ́rẹ̀ẹ́, sí 0–1 sí Jamaica.[5]
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Àdàkọ:Soccerway
- ↑ 2.0 2.1 2.2 "Onyinyechi Zogg". FC Zürich (in Èdè Jámánì). Archived from the original on 28 February 2022. Retrieved 19 June 2021.
- ↑ "Salome Zogg". Global Sports Archive. Retrieved 19 June 2021.
- ↑ 4.0 4.1 "Onyinyechi Zogg – Women's Soccer". Monroe College Athletics. Retrieved 19 June 2021.
- ↑ "Match Report of Jamaica vs Nigeria – 2021-06-10 – FIFA Friendlies – Women". Global Sports Archive. Retrieved 19 June 2021.