Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò "Ẹ̀bùn Ọ́skà"

Jump to navigation Jump to search
18 bytes removed ,  16:40, 15 Oṣù Kàrún 2020
Kò sí ìsọníṣókí àtúnṣe
}}
 
'''Ẹ̀bùn ìmọ̀ ìjìnlẹ̀ fíìmù Amẹ́ríkàAkádẹ́mì''' tàbí '''OscarẸ̀bùn Ọ́skà''' jẹ́ ẹ̀bùn ìmọ̀ ìjìnlẹ̀ fíìmù tí American Academy of Motion Picture Arts and Sciences ma ń fún olùdarí eré, òṣèrè àtí olùkọ̀tàn fún iṣẹ́ takuntakun ní ilé iṣẹ́ fíìmù.<ref>{{cite web |url = http://www.oscars.org/aboutacademyawards/index.html |title = About the Academy Awards |publisher = Academy of Motion Picture Arts and Sciences |accessdate = April 13, 2007 |archiveurl = http://web.archive.org/web/20070407234926/http://www.oscars.org/aboutacademyawards/index.html <!-- Bot retrieved archive --> |archivedate = April 7, 2007}}</ref> Ayẹyẹ ẹ̀bùn yìí jẹ́ ìkan lára àwọ́n ayẹyẹ èbùn tó lókìkí jùlọ ní gbogbo àgbáyé. Osì tún jẹ́ Ayẹyẹ ẹ̀bùn tó pẹ́ júlọ tí ó si ma ń dàgbeléwò lórí ẹ̀rọ amóùnmáwòran ní orílẹ̀ èdè tó ju igba lọ. Aẁọn ẹ̀bùn ìmọ̀ ìjìnlẹ̀ fíìmù bi tiẹ̀ ni [[Grammy Awards]] (fún orin), [[Emmy Awards]] (fun amóùnmáwòran), àti [[Tony Awards]] (fún tíát̀à)
 
== Ìtọ́kasí ==

Ètò ìtọ́sọ́nà