Wikipedia:Àwọn alámùójútó

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Àwọn Alámójútó lè ràn ẹ́ lọ́wọ́ láti pa ojú ewé kan rẹ́, dínà mọ́ àwọn bàsèjẹ́ kí wọ́n má lè ṣiṣẹ́ mọ́. Bí wọ́n bá sì dínà mọ́ ọ tí o sì fẹ́ kí wọ́n ṣínà tàbí gbà ọ́ wọlé padà, o lè kàn sí alámójútó tó dínà mọ́ ọ lórí ' ìkànì e meèlì rẹ̀ ' tí ó wà ní apá òsì ojú ewé oníṣẹ́ rẹ̀.

Àwọn Alámójútó
Àwọn Alámùójútó tẹ́lẹ̀