Páùlù ará Társù
Paul the Apostle | |
---|---|
Ananias restoring the sight of Saint Paul by Pietro da Cortona | |
Apostle to the Gentiles | |
Born | c. 10 AD in Tarsus[Acts 22:3] |
Died | c 67 AD[1] in Rome[1] |
Venerated in | All Christianity |
Major shrine | Basilica of Saint Paul Outside the Walls |
Feast | January 25 (The Conversion of Paul) February 10 (Feast of Saint Paul's Shipwreck in Malta) June 29 (Feast of Saints Peter and Paul) November 18 (Feast of the dedication of the basilicas of Saints Peter and Paul) |
Attributes | sword |
Patronage | Missions; Theologians; Gentile Christians; |
Páálù[lower-alpha 1] (tí àwọn míràn mọ̀ sí Saalu ara Tarsus;[lower-alpha 2], Páálù àpọ́sítélì[2] tàbí Páálù ẹni mímọ́,[3] jẹ́ ọ̀kan lára àwọn Àpọ́sítélì mejemu titun tí ó polongo iṣẹ́ ìránṣẹ́ Jesu Kristi.[4] Páálù wà lára àwọn ènìyàn nígbà ayé àwọn Àpọ́sítélì tí wón kà se pataki ní ìtàn.[3][5] Ó dá ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìjọ sílè ní Asia àti Europe.[6]
Gégé bí ìwé májẹ̀mú tuntun ìṣe àwọn Àpọ́sítélì ṣe ṣàlàyé, Páálù je Farisí.[7] Ó sì kópa nínú sí isenunibinu ìjọba Róòmù sí àwọn Kristẹni àkọ́kọ́,[8] ní Jerúsálẹ́mù kí ó tó di pé ó di ẹni ìgbàlà.[note 1] Ìgbà di ẹ̀ lẹ́yìn ìgbà tí ó fi owó sí isekupa Stefani,[9] Páálù ń rìn ìrìn àjò lọ sí Damásíkù láti wá àwọn Kristẹni àti láti "kó wọn ní ìdè wá sí Jerúsálẹ́mù"(ESV).[10] Ní àárín ọjọ́, imole ńlá tàn sí Paalu àti àwọn tó yi ká, èyí mú kí ó ṣubú, tí Jesu sì bẹ̀rẹ̀ lọ́wọ́ rẹ̀ wí pé "kí ló dé tí ó fi ń ṣe inúnibíni sí mi".[11][12]
Ojú Paalu kò láti ríran,[13] à si pàṣẹ fun láti wo ìlú náà. Iriran Paalu padà bò sípò lẹ́yìn ìjọ mẹ́ta nígbà tí Ananíà ará Damásíkù gbàdúrà fun. Léyìn n kan wò yín, wọ́n ṣe itebomi fún Paalu, ó sì bẹ̀rẹ̀ sí polongo pé Jesu ni olùgbàlà àti ọmọ Olorun.[14] Bi idasi-meji ìwé ìṣe àwọn Àpọ́sítélì sọ̀rọ̀ nípa ìgbé ayé Paalu.
Àwọn míràn gbàgbọ́ pé Paalu ni ó ko mẹ́rìnlá nínú àwọn ìwé metadinlogbon ti Májẹ̀mú Láéláé.[15] Bí ó ti lè jẹ́ wípé àríyànjiyàn wà láàrin àwọn ọ̀jọ̀gbọ́n lórí bóyá òhun ló kọ àwọn míràn nínú àwọn ìwé yìí àbí òun kọ́.
Otún le ka
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Àwọn Ìtókasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ 1.0 1.1 Harris, p. 411
- ↑ Brown 1997, p. 442.
- ↑ 3.0 3.1 Sanders 2019.
- ↑ Powell 2009.
- ↑ Dunn 2001, Ch 32.
- ↑ Rhoads 1996, p. 39.
- ↑ Acts 26:5 ESV
- ↑ Dunn 2009, pp. 345–346.
- ↑ Acts 8:1 ESV
- ↑ Acts 9:2 ESV
- ↑ Acts 26:13–14 ESV
- ↑ Acts 22:7–9 ESV
- ↑ Acts 22:11 ESV
- ↑ Acts 9:3–22 ESV
- ↑ Brown 1997, p. 407.
- ↑ Látìnì: Paulus; Èdè Grííkì Ayéijọ́un: Παῦλος; Àdàkọ:Lang-cop; Àdàkọ:Lang-hbo
- ↑ Àdàkọ:Lang-hbo; Lárúbáwá: بولس الطرسوسي; Èdè Grííkì Ayéijọ́un: Σαῦλος Ταρσεύς [Saũlos Tarseús] error: [undefined] error: {{lang}}: no text (help): text has italic markup (help); Àdàkọ:Lang-tr; Látìnì: Paulus Tarsensis
Àṣìṣe ìtọ́kasí: <ref>
tags exist for a group named "note", but no corresponding <references group="note"/>
tag was found