Jump to content

Pákò

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Bunches of teeth cleaning twigs displayed near Kalka, India
Teeth cleaning twig

Pákò tàbí Orín jẹ́ egbò igi, tàbí ẹ̀ka igi tí a gé, tí a jẹ láti fi ṣe ìmọ́ tótó ẹnu, fe eyín tí ó ti ń kẹ̀ ṣe tàbí fi bá kòkòrò ẹnu wọ̀yá ìjà.[1]

Pa ko ni ó ní àwọn ànfàní wọ̀nyí:

  • Ó ma ń fe ẹnu mọ́ ju ohun èlò ìfọnu Brush lọ.[2]
  • Pákò kò ní èròjà Kẹ́míka kan kan tí ó lè pani lára rárà. [3]
  • Ó ń mú àdínkù bá owó níná ní ọ̀nà (0-16%) yàtọ̀ọ̀ sí Ohun èlò ìfọyín búrọ́ṣì.
  • Ó dára fún ìlera ẹnu. [4]

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. Malik, Aeeza S; Shaukat, Malik S; Qureshi, Ambrina A; Abdur, Rasheed (2013-01-05). "Comparative Effectiveness of Chewing Stick and Toothbrush: A Randomized Clinical Trial". North American Journal of Medical Sciences 6 (7). doi:10.4103/1947-2714.136916. PMID 25077082. https://www.ncbi.nlm.nih.gov/pmc/articles/PMC4114011/. Retrieved 2019-12-31. 
  2. Hooda, Anita; Rathee, Manu; Singh, Janardhan (2009-12-31). "Chewing Sticks In The Era Of Toothbrush: A Review". The Internet Journal of Family Practice 9 (2). http://ispub.com/IJFP/9/2/4968. Retrieved 2019-12-31. 
  3. "African 'chewing sticks' work as well as toothbrushes". EurekAlert!. 2000-03-01. Archived from the original on 2019-12-31. Retrieved 2019-12-31. 
  4. "Chewing sticks versus tooth brush". The Nation Newspaper (in Èdè Latini). 2019-01-12. Retrieved 2019-12-31. 

÷