Pál Schmitt

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search
Pál Schmitt
SchmittPal-2011-01 EuropaPont.jpg
Aare ile Hungari
In office
6 August 2010 – 2 April 2012
Alákóso Àgbà Viktor Orbán
Asíwájú László Sólyom
Arọ́pò László Kövér (Acting)
Speaker of the National Assembly
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
14 May 2010
Asíwájú Béla Katona
Personal details
Ọjọ́ìbí 13 Oṣù Kàrún 1942 (1942-05-13) (ọmọ ọdún 77)
Budapest, Hungary
Ẹgbẹ́ olóṣèlu Fidesz
Profession Fencer

Pál Schmitt (ojoibi 13 May 1942 ni Budapest) je oloselu ara Hungari ati lowolowo Agbenuso Ile Asofin ile Hungari lati 14 May 2010. O je didiboyan bi Aare ile Hungari pelu ibo 263 si 59 ni Ile Asofin ile Hungari, o bo si ori aga ni 5 August 2010 de 2012.Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]