Pablo Picasso
Ìrísí
Orúkọ yìí lo àṣà ìṣorúkọ ní èdè Spéìn; àkọ́kọ́ tàbí orúkọ ìdílé bàbá ni Ruiz èkejì tàbí orúkọ ìdílé ìyà ni Picasso.
Pablo Picasso | |
---|---|
Pablo Picasso in 1962 | |
Ilẹ̀abínibí | Spanish |
Pápá | Painting, Drawing, Sculpture, Printmaking, Ceramics |
Training | José Ruiz y Blasco (father), Real Academia de Bellas Artes de San Fernando |
Movement | Cubism |
Iṣẹ́ | Les Demoiselles d'Avignon (1907) Guernica (1937) The Weeping Woman (1937) |
Pablo Ruiz y Picasso, to gbajumo bi Pablo Picasso (Pípè: [ˈpaβlo piˈkaso], 25 October 1881 – 8 April 1973), je akun àworan, agbere, atewe, oniseamo, ati onigbajamo oriitage ara Spein to lo opo gbogbo ojo aye re ni Fransi.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |