Padita Agu
Ìrísí
Padita Agu tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kẹtàlá oṣù kẹwàá ọdún 1980 (13th October 1980)[1] jẹ́ òṣèrébìnrin sinimá àgbéléwò ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ó ti kópa lóríṣiríṣi nínú àwọn sinimá-àgbéléwò èdè Gẹ̀ẹ́ṣì, ṣùgbọ́n ipa tó kó nínú sinimá àgbéléwò kan tí àkọ́lé rẹ̀ ń "The Last Three Digits" lọ́dún 2015 lo sọ ọ́ di gbajúmọ̀ òṣèré ìlúmọ̀ọ́kà. [2] [3]
Padita Agu | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | 13th October 1980 |
Ọmọ orílẹ̀-èdè | Nàìjíríà |
Iṣẹ́ | òṣèrébìnrin |
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Learn about Padita Agu". Famous Birthdays. Retrieved 2020-03-08.
- ↑ "I WAS YOUNG AND NAIVE, SAYS PADITA AGU ON FAILED MARRIAGE - Latest Nigeria News, Nigerian Newspapers, Politics". Latest Nigeria News, Nigerian Newspapers, Politics (in Èdè Latini). 2019-11-16. Retrieved 2020-03-08.
- ↑ Published (2015-12-15). "I don’t feel I’m famous – Padita Agu". Punch Newspapers. Retrieved 2020-03-08.