Jump to content

Pamela Adlon

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Pamela Adlon
Adlon in 2017
Ọjọ́ìbíPamela Fionna Segall[1][2]
6 Oṣù Keje 1966 (1966-07-06) (ọmọ ọdún 58)[3]
New York City, U.S.
Ọmọ orílẹ̀-èdè
  • United States
  • United Kingdom[4][5]
Iṣẹ́Actress
Ìgbà iṣẹ́1982–present
Olólùfẹ́
Felix O. Adlon
(m. 1996; div. 2010)
Àwọn ọmọ3, including Gideon Adlon and Odessa A'zion

Pamela Fionna Adlon ( /ˈædlɒn/) (tí wọ́n bí ní July 6, 1966) jẹ́ òṣèrébìnrin ti Orílẹ̀ èdè America. Ó gbajúgbajà fún lílo ohùn rẹ̀ láti fi ṣe ẹ̀dá-ìtàn Bobby Hill nínú fíìmù King of the Hill (1997–2010).[6]

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named tvg
  2. Stated on Finding Your Roots, January 25, 2022
  3. Adlon, Pamela. "Finding your roots". PBS. 
  4. Tube, Stage. "VIDEO: Pamela Adlon Revisits Her Bobby Hill Voice on THE TONIGHT SHOW". BroadwayWorld.com. 
  5. "Pamela Adlon wants you to know she has your back". Fortune. 
  6. Gross, Terry (January 4, 2012). "Pamela Adlon: From 'Hill' Kid To 'Californication'". Fresh Air. NPR. Retrieved June 4, 2014.