Jump to content

Patience Avre

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Patience Avre
Personal information
Ọjọ́ ìbí10 Oṣù Kẹfà 1976 (1976-06-10) (ọmọ ọdún 48)
Ibi ọjọ́ibíNigeria
Ìga1.72m
Playing positionForward
National team
YearsTeamApps(Gls)
2000Nigeria women's national football team16(1)
† Appearances (Goals).

Patience Avre jẹ agbabọọlu lobinrin tẹlẹ ri ti a bini 10, óṣu june ni ọdun 1976. Arabinrin na ti ṣere fun ọrilẹ ede naigiria gẹgẹbi ipo forward[1][2].

  • Patience ti kopa ninu Cup FIFA awọn obinrin agbaye ni ọdun 1995, 1999 ati 2003. Arabinrin naa ti kopa ninu olympic to waye ni ọdun 2000[3][4]
  1. https://www.eurosport.com/football/patience-avre_prs414754/person.shtml
  2. https://fbref.com/en/players/63b23cd3/Patience-Avre
  3. https://www.fifa.com/tournaments/womens/womensworldcup/sweden1995/teams/1882893
  4. "Ẹda pamosi". Archived from the original on 2022-05-29. Retrieved 2022-05-29.