Jump to content

Patoo Abraham

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́


Patoo Abraham (ti wón bíi ní ọdún 1966) jẹ́ aṣèwó àti alátìlẹ́yìn ẹ̀tọ́ àwọn aṣèwó ní Nàìjíríà, tó ń bẹ̀bẹ̀ fún lílàṣẹ̀ fún iṣẹ́ aṣèwó ní Nàìjíríà àti ìtẹ̀síwájú àwọn obìnrin tó ń ṣe iṣẹ́ yìí kúrò ní ètò ìwà ọdaran. Ni bíi ọdún 2014, ó jẹ́ olórí African Sex Workers Alliance (ASWA) ní Nàìjíríà.[1][2] Ó tún jẹ́ Ààrẹ ẹgbẹ́ Women of Power Initiative (WOPI), àjọ alágbára tó dá sílẹ̀ láti mú ìmúdàgba bá iṣẹ́ aṣèwó ní Nàìjíríà.[3][4] Patoo Abraham ti ṣe ọ̀pọ̀ ìfẹnusọ̀ lórí àwọn òpópónà èko lòdì sí ìkà àti àìṣèbàbò fún àwọn tó ń ṣe iṣẹ́ aṣèwó.[5]

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àdàkọ:Prostitution


Àdàkọ:Nigeria-activist-stub Àdàkọ:Sex-stub