Patricia S. Cowings

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Patricia S. Cowings
NASA photograph of Dr. Patricia S. Cowings
Ọjọ́ìbíPatricia S. Cowings
(1948-12-15)Oṣù Kejìlá 15, 1948
The Bronx, New York City, New York, U.S.
Orílẹ̀-èdèAmerican
Ẹ̀kọ́State University of New York at Stony Brook (BA Psychology); University of California Davis (MA Psychology; Ph.D. Psychology)
Iṣẹ́Psychophysiology
Olólùfẹ́
Dr. William B. Toscano
(m. 1980)
Parent(s)
  • Albert S. Cowings
  • Sadie B. Cowings
Awards
  • Candace Award
  • NASA Individual Achievement Award
  • Black Engineer of the Year Award
  • AMES Honor Award for Technology Development
  • NASA Space Act Award for Invention
  • National Women of Color Technology Award
  • NASA Space Act Board Award
  • Ames African American Advisory Group's (AAAG) Achievement Award
  • Celestial Torch Award from the National Society of Black Engineers (NSBE) in Los Angeles

Patricia S. Cowings (tí wọ́n bí ní December 15, 1948) jẹ́ psychophysiologist ti aerospace. Òun ni obìnrin ará America àkọ́kọ́ tí àwọn NASA máa fún ní ìdánilẹ́kọ̀ọ́ láti di awòràwọ̀ onísáyẹ̀ǹsì.[1] Bó tilẹ̀ jẹ́ pé ó jẹ́ ẹnìkejì fún ìrìn-àjò orí space ní ọdún 1979, àmọ́ kò rìn ìrìn-àjò lọ sí.[2] Ó gbajúmọ̀ fún ẹ̀kọ́ rẹ̀ nínú ìmọ̀ physiology ti àwọn awòràwọ̀ ní space, àti fú ìrànwọ́ rẹ̀ láti wá ojútùú sí àárè àwọn awòràwọ̀.[3][4][5]

Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé àti ìdílé rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Wọ́n bí Cowings sí ìlú The Bronx, ní New York City ní December 15, ọdún 1948. Òun ni ọmọbìnrin kan ṣoṣo ti Sadie B. àti Albert S. Cowings. Sadie jẹ́ aṣèrànwọ́ olùkọ́ ní ilé-ìwé àwọn ọ̀jẹ̀ wẹ́wẹ́, Albert sì jẹ́ onílé-ìtàjà. Ó ní àwọn ẹgbọ́nkùnrin mẹ́ta mìíràn tí wọ́n di ọ̀gágun, olórin àti akọ̀ròyìn. Àwọn òbí rẹ̀ rí ẹ̀kọ́ gẹ́gẹ́ bí i "ọ̀nà láti kúrò ní Bronx". [6]

Àtòjọ àwọn àmì-ẹ̀yẹ rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àwọn iṣẹ́-ìwádìí àti ẹ̀kọ́ rẹ̀ ti gba ọ̀pọ̀lọpọ̀ àmì-ẹ̀yẹ, bí i:[7]

  • Candace Award, National Coalition of 100 Black Women (1989)[8]
  • NASA Individual Achievement Award (1993)
  • Black Engineer of the Year Award (1997) [9]
  • AMES Honor Award for Technology Development (1999)
  • NASA Space Act Award for Invention (2002)
  • National Women of Color Technology Award (2006) [9]
  • NASA Space Act Board Award (2008) [9]
  • Ames African American Advisory Group's (AAAG) Achievement Award (2010) [9]
  • Celestial Torch Award from the National Society of Black Engineers (NSBE) in Los Angeles (2014) [9]

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Cowings, Patricia. "Patricia S. Cowings, Ph. D". thebannekerinstitute.org. The Benjamin Banneker Institute for Science and Technology. Archived from the original on April 12, 2016. 
  2. "Patricia Cowings, PhD, NASA psychopysiologist". American Psychological Association. Archived from the original on February 10, 2015. 
  3. Wayne, Tiffany (2011). American Women of Science Since 1900. Santa Barbara, CA: ABC CLIO, LLC. pp. 320–321. ISBN 978-1-59884-158-9. https://archive.org/details/americanwomensci00phdt. 
  4. Notable Black American women. Smith, Jessie Carney, 1930-, Phelps, Shirelle. Detroit: Gale Research. 1996. ISBN 9780810391772. OCLC 24468213. https://archive.org/details/notableblackamer00jess. 
  5. Oakes, Elizabeth H. (2007). Encyclopedia of world scientists (Rev ed.). New York: Facts on File. ISBN 9780816061587. OCLC 83610106. 
  6. Gubert, Betty Kaplan (2002). Distinguished African Americans in aviation and space science. Sawyer, Miriam., Fannin, Caroline M.. Westport, Conn.: Oryx Press. ISBN 9781573562461. OCLC 47013254. https://archive.org/details/distinguishedafr00gube. 
  7. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named Wayne2
  8. "CANDACE AWARD RECIPIENTS 1982-1990, Page 2". National Coalition of 100 Black Women. Archived from the original on March 14, 2003. 
  9. 9.0 9.1 9.2 9.3 9.4 "Patricia S. Cowings". NASA Human Systems Integration Division. Archived from the original on December 2, 2016.