Jump to content

Patti LaBelle

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Patti LaBelle
LaBelle in Zang Toi at The Heart Truth’s Red Dress Collection Fashion Show, 2011
LaBelle in Zang Toi at The Heart Truth’s Red Dress Collection Fashion Show, 2011
Background information
Orúkọ àbísọPatricia Louise Holte
Wọ́n tún mọ̀ọ́ bíiPatricia Edwards
Ọjọ́ìbí24 Oṣù Kàrún 1944 (1944-05-24) (ọmọ ọdún 80)
Ìbẹ̀rẹ̀Philadelphia, Pennsylvania, United States
Irú orinR&B, soul, pop, soft rock, gospel
Occupation(s)Singer-songwriter, actress
Years active1958–present
LabelsEpic, Philadelphia Int'l, MCA, Def Soul Classics, Umbrella, Bungalo
Associated actsLabelle, Michael McDonald, Mary J. Blige
Websitepattilabelle.com

Patricia Louise Holte-Edwards (ojoibi May 24, 1944), to gbajumo pelu oruko ori-itage, Patti LaBelle, je akorin to gba Ebun Grammy, olukowe ati osere to ti lo to 50 odun nidi orin. LaBelle lo odun 16 bi akorin asiwaju egbe Patti LaBelle and the Bluebelles, ti won yi oruko won si Labelle ni ibere ewadun 1970, ti won si gbe orin disco "Lady Marmalade" jade to si gbajumo titi di oni.