Paulette Goddard

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search
Paulette Goddard

Paulette Goddard (ti orúkọ abisọ rẹ jẹ Marion Levy) gbé ayé lati ọjọ kẹta oṣù kẹfà ọdún 1910 titi dé ọjọ ketalelogun oṣù kẹrin ọdún 1990. O jẹ òṣèré ọmọ orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà.


Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]