Paulus Hamutenya
Ìrísí
Haufiku Paulus Hamutenya (tí wọ́n bí ní c. 1884, Oukwanyama, Angola — tí ó sì fi ayé sílẹ̀ ní ọjọ́ Kejìlá oṣù kẹwàá ọdún 1932[1]) jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ẹni méje àkọ́kọ́ tí Matti Tarkkanen yàn láti jẹ́ olùsọ àgùntàn ní Oniipa, Ovamboland, ní ọdún 1925.[2]
Hamutenya jẹ́ ọmọ Hamutenya gwaNghililewanga àti Ndayapi yaKavengula. A bi sí Onandjokwe ní c. 1884, a sì ṣe ìrìbọmi rẹ̀ ní ìlú kan náà ní ọdún 1919.[1]