Pavlos Kountouriotis

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Pavlos Kountouriotis

Pavlos Kountouriotis (Gíríkì: Παύλος Κουντουριώτης, 9 April 1855 - 22 August 1935) je Griiki Ogagun ojuomi ati akoni ologun ojuomi nigba Awon Ogun Balkan ati Aare ekini ati eketa orile-ede Griisi.


Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]