Jump to content

Pedro Pires

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Pedro Verona Rodrigues Pires
President of Cape Verde
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
22 March 2001
Alákóso ÀgbàJosé Maria Neves
AsíwájúAntónio Mascarenhas Monteiro
Prime Minister of Cape Verde
In office
8 July 1975 – 4 April 1991
ÀàrẹAristides Pereira
António Mascarenhas Monteiro
AsíwájúOffice created
Arọ́pòCarlos Veiga
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí29 Oṣù Kẹrin 1934 (1934-04-29) (ọmọ ọdún 90)
Fogo, Cape Verde
Ẹgbẹ́ olóṣèlúPAICV
(Àwọn) olólùfẹ́Adélcia Barreto Pires

Pedro Verona Rodrigues Pires (Pípè ni Potogí: [ˈpedɾu vɨˈɾonɐ ʁuˈdɾiɡɨʃ ˈpiɾɨʃ]; ojoibi 29 April 1934) ni Aare orile-ede Cape Verde lati March 2001. Ki o to di Aare, ohun ni Alakoso Agba lati 1975 de 1991.