Perpetua Nkwocha

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Perpetua Nkwocha
Perpetua_Nkwocha_(cropped)
Nwocha in May 2013
Personal information
OrúkọPerpetua Ijeoma Nkwocha
Ọjọ́ ìbí3 Oṣù Kínní 1976 (1976-01-03) (ọmọ ọdún 48)
Ìga1.80 m
Playing positionMidfielder
Club information
Current clubClemensnäs IF (coach)
Senior career*
YearsTeamApps(Gls)
2007–2014Sunnanå SK139**(65**)
National team
1999–2015Nigeria women's national football team99(80)
Teams managed
2015–Clemensnäs IF
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only and correct as of 16:41, 29 June 2015 (UTC)
**From 2008–2014.

† Appearances (Goals).

‡ National team caps and goals correct as of 15:56, 17 June 2015 (UTC)

Perpetua Nkwocha jẹ ọkan lára àwọn agbábọ́ọ̀lú-ẹlẹ́sẹ̀ lóbìnrin tí a bíní ọjọ́ kẹta, oṣù kínní odún 1976. Arábìnrin náà ṣeré tẹ́lẹ̀ rí fún Swedish club Sunnanå SK àtipé agbábọ́ọ̀lú náà jẹ́ captain tẹ́lẹ̀ rí fún team àpapọ àwọn obìnrin ilẹ̀ Nàìjíríà lórí bọ́ọ̀lù-ẹlẹ́sẹ̀[1][2][3].

Àṣeyọri[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  • Perpetua kópa nínú eré ìdíje àwọn obìnrin ilẹ̀ áfíríkà ní ọdún 2004[4].
  • Agbábọ́ọ̀lú-ẹlẹ́sẹ̀ náà kópa nínú Cup FIFA àwọn obìnrin àgbáyé ní ọdún 2003, 2007, 2011 àti 2015[5][6].

Itọkasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. https://www.eurosport.com/football/perpetua-nkwocha_prs281835/person.shtml
  2. https://fbref.com/en/players/b4945edc/Perpetua-Nkwocha
  3. https://sportsbrief.com/football/super-falcons/17140-asisat-oshoala-picks-snubs-mercy-akide-selects-super-falcons-icon-perpetua-nkwocha-lead-5-aside-dream-team/
  4. https://www.goal.com/en-ng/news/4093/nigerian-football/2012/10/24/3473703/perpetua-nkwocha-sets-15-goal-target-for-african-women
  5. https://www.goal.com/en-ng/news/12072/nigeria-women/2015/05/21/11935672/super-falcons-land-in-canada-with-perpetua-nkwocha-for-world
  6. https://www.thecable.ng/golden-oldie-nkwocha-makes-world-cup-team/amp