Jump to content

Peters Ijagbemi

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Peters Ijagbemi jẹ́ òṣèré ọmọ ìlú Ìbàdàn n'ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ l'órílẹ̀-èdè Nigeria.[1] Ó kàwé àkọ́bẹ̀rẹ̀ ní ilé-ẹ̀kọ́ Champions Academy ní Ìbàdàn, bẹ́ẹ̀ ló lọ sí Titcombe College ni Ìpínlẹ̀ Kogí . Ó kàwé gb'oyè àkọ́kọ́ àti kejì ni Ahmadu Bello University, Zaria ní Ìpínlẹ̀ Kaduna àti University of Lagos.[2]

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. Fasan, Yewande (2023-12-08). "My marriage ended because I didn't flaunt my wife". The Nation Newspaper. Retrieved 2024-11-15. 
  2. Ayeni, Victor (2024-02-23). "Before Stardom With... Peter Ijagbemi". Punch Newspapers. Retrieved 2024-11-15.