Philosophiæ Naturalis Principia Mathematica

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Philosophiæ Naturalis Principia Mathematica
Title page of Principia, first edition (1687)
Olùkọ̀wéSir Isaac Newton
Àkọlé àkọ́kọ́Philosophiæ Naturalis Principia Mathematica
LanguageNew Latin
Publication date
1687 (1st ed.)
Published in English
1728
LC ClassQA803 .A53

Philosophiæ Naturalis Principia Mathematica (Èdè Látìnì fún Àwọn Ìpilẹ̀sẹ̀ Matimátíìkì fún Imọ̀-òye Adánidá, Mathematical Principles of Natural Philosophyèdè Gẹ̀ẹ́sì),[1] tí wọ́n tún tọ́ka sí bíi Principia ( /prɪnˈsɪpiə,_prɪnˈkɪpiə/ prinkípíà), ni ìwé apá mẹ́ta tí Isaac Newton kọ ní èdè Látìnì, tí wọ́n kọ́kọ́ tẹ̀jáde ní 5 July ọdún 1687.[2] Lẹ́yìn tí Newton ṣe àtúnṣe sí àtẹ̀jáde àkọ́kọ́ ìwé yìí,[3] ó tún tún tẹ̀ jáde ní ọdún 1713 àti ọdún 1726. Principia ṣe àkọsílẹ̀ àwọn òfin ìmúrìn Newton, tí wón jẹ́ ìpìlẹ̀ ìṣiṣẹ́-ẹ̀rọ ògbólògbó; òfin ìfàmọ́ra gbogbo únkan Newton; àtí ìwájáde àwọn òfin ìmúrìn plánẹ́tì Kepler (tí Kepler kọ́kọ́ fi first obtained ọgbọ́n ìrírí wá jáde).

Awọn ẹda[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]