Jump to content

Pi

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Ti idamita iyipo kan ba je 1, iyika re yio je π

Pi tabi π (tabi Pai) jẹ́ ọ̀kan nínú oǹkà ìmọ̀ Ìṣirò (Mathematics) tó ṣe pàtàkì. Ó fé tó 3.14159. Ó dúró fún ìpín ìyíká obirikiti mọ́ ìlà ìdáméjì rẹ̀.Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]