Jump to content

Plantain mosa

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Plantain mosa jẹ́ ohun ìpanu tí Orílẹ̀ èdè Nàìjíríà tí ó sì dàbí ohun tí a mọ̀ sí small chops. E yí tí ó dàbí rẹ̀ ni wọ̀nyí grilled chicken, spring roll, samosa àti puff puff.[1]

Mosa fẹ́ dàbí Ghanaian Tatale à fi èyí tí a fi ọ̀gẹ̀dẹ̀ tó ti pọ́n jù ṣè tàbí ẹyin, fúláwà àti èyí tí a fi ọ̀gẹ̀dẹ̀ tòun tìkára rẹ̀ ṣe, atalẹ àti èròjà aládùn. Pọpọ́fùù àti Mosa fẹ́ jọra yàtọ̀ sí Mosa tí ó ní òórùn ọ̀gẹ̀dẹ̀.[2][3]

Àwọn èròjà yòókù tí a fi ń se plantain Mosa ni wọ̀nyí alùbọ́sà, òróró, bonnet pepper àti yeast. Dín Ọ̀gẹ̀dẹ̀ lílọ̀ náà títí yóò fi di búráwùn   pẹ̀lú èròjà yòókù  A lè fi Mosa ṣe oúnjẹ òwúrọ̀ nílé wa.[4]

Nigeria cuisine

True Plantain

Snack

Àwọn Ìtọ́kasi

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "6 delicious reasons why plantain is a culinary breakthrough". Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2017-02-08. Retrieved 2022-06-27. 
  2. "How To Prepare Plantain Mosa". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2022-04-01. Archived from the original on 2022-06-27. Retrieved 2022-06-27. 
  3. Onyeakagbu, Adaobi (2018-09-27). "Ghanaian Tatale meets Nigerian plantain mosa". Pulse Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-06-27. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
  4. "Three recipes using overripe plantain". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-03-10. Retrieved 2022-06-27. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]