Precious Dede
Ìrísí
Personal information | |||
---|---|---|---|
Orúkọ | Precious Uzoaru Dede | ||
Ọjọ́ ìbí | 18 Oṣù Kínní 1980 | ||
Playing position | Goalkeeper | ||
Club information | |||
Current club | Ibom Queens | ||
2009 | Arna-Bjørnar | 16 | (0) |
2010–?? | Delta Queens | ||
Ibom Queens | |||
National team‡ | |||
Years | Team | Apps† | (Gls)† |
–2016 | Nigeria women's national football team | 99 | (0) |
† Appearances (Goals). ‡ National team caps and goals correct as of 15:46, 17 June 2015 (UTC) |
Precious Dede ti a bini 18, óṣu January ni ọ̀dun 1980 jẹ agbabọọlu lobinrin ilẹ Naigiria ti o si ti ṣiwọ ìṣe. Goalkeeper naa ti ṣiṣẹ fun óriṣirìṣi club bi Delta Queens, FC Ibom Queens and Arna-Bjorna[1]
Aṣeyọri
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Dede ti kopa ninu Cup idije Awọn obinrin Agbaye ni ọdun 2003, 2007, 2011 ati 2015[2].
- Arabinrin naa ti kopa ninu idije awọn obirin ilẹ afirica lẹ̀ẹmeji ni ọdun 2010 ati 2014[3].