Priscilla Achapka

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Priscilla Achapka
Orílẹ̀-èdè
Iṣẹ́
  • Nigerian environmental activist
Notable work
  • Women Environment Programme (WEP)

Priscilla Achapka jẹ ajijagbara onimọ ayika ti ilẹ Naijiria. Priscilla jẹ oludasilẹ ati ààrẹ agbaye ti awujọ awọn obinrin ti wọn mujoto ayika eyi ti ólóyinbo pe ni Women Environment Programme (WEP)[1][2]. Ajọ yi jẹ eyi ti o maa npèsè alagbero ojutu fun iṣóró óójójumọ[3]. Ninu eto ayika ti UN, Priscilla ni a fijẹ́ alabojuto keji[4].

Ìgbèsi Áyè ati Ẹkọ Priscilla Achapka[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Priscilla fẹ ọkọ ni ọmọ mẹrin dinlógun ti o si bi ọmọ mẹta fun. Ọkọ naa ku to si sọ arabinrin naa di ópó kèkèrè[5].

Arabinrin naa lọ si ile iwe to si gba ami ọye ti ẹkọ lori igbegba ati amujuto ọrọ aje ti oloyibo pe ni Developmental Studies, Business Administration and Management.Lẹyin naa lo tẹsiwaju ninu ẹkọ rẹ to si pari Ph.D lati ilè iwè giga ti Business Engineering ati Amòjuto. Arabinrin naa gba iwè ẹri lati ilè iwè giga to da lóri ọrọ aje ti Havard[6].

Iṣẹ Priscilla[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Lati ọdun 1989 de 2001, Achapka ṣiṣẹ ni ile ifowopamọ ti Savannah to si bẹrẹ si ni kẹkọ lori iṣóró ayika lati lè ṣiṣẹ lori imọ ayika. Iṣẹ rẹ da lori fifi ọrọ nipa abo tabi akọ si amujuto ómi[7]. Arabinrin naa ṣiṣẹ gẹgẹbi àṣoju Awujọ àgbègbè Awọn óbinrin pẹlu summit ti óju ọjọ UN. Priscilla ni ayan lati ṣè amójuto ètò ayika ti United Nations lori awujọ awọn óbinrin eyi ti ólóyinbo pe ni Women's Major Group. Ìṣẹ rẹ da lori titọ awọn awujọ óbinrin lapapọ ni óri ofin ayika ti UN, ólugbọwọ fun ẹto naa[8].

Priscilla jẹ̀ alaga ti awujọ ti Abaagu to da lori fifi ọdọ si iṣẹ̀ ati amojuto awujọ. Ni ọdun 2012, Priscilla kopa ninu idunadura to waye ni alapejọ ti UN lori Idagbasoke ti o pe (Rio+20). Arabinrin naa ti sọrọ ni Àpejọ ti UN ni Nairobi lori pataki ninu ẹtọ ọmọ eniyan ti awọn óbinrin lori ijagbara ayika[9][10][11].

Achakpa gba ipo ti oludari apapọ fun amojuto omi ati ibaṣèpọ eyi ti ólóyinbo pe ni Water Supply and Sanitation Collaborative Council (WSSCC), ọkan lara eto ti UN gbe kalẹ fun iṣẹ Project ti ólóyinbo pe ni United Nations Office for Project Services (UNOPS). Ni ọdun 2015, Vogue Magazine fi si ori iwe lori apejọ ti UN to da lori ayipada oju ọjọ ti wọn si ri bi ọkan lara mẹtala gẹgẹbi eyi ti òlòyinbo pe ni "formidable women leading the way[12][13]"

Ami Ẹyẹ ati Idanilọla[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Achakpa jẹ ti Ashoka lati ọdun 2013[3]. Priscilla ni a sọ ni Eco Hero lati ọdọ Germany's Deutsche Welle ati Nigeria's Channels Television[14].

Priscilla gba ami ẹyẹ ti imọ tuntun lori ayika lati ọdọ Deutsche Welle[14]. . Achakpa ni a yẹsi lati ọdọ Nobel Women's Initiative gẹgẹbi ajijagbara.

Awọn Itọkasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Ekele, Jiata (2021-12-17). "Nigeria Climate Change Act: CSDevNet, Non-State Actors strategise on Implementation". CSDevNet. Retrieved 2023-09-06. 
  2. "Priscilla Achakpa". Sustainable Futures in Africa. 2019-12-19. Archived from the original on 2023-09-25. Retrieved 2023-09-06. 
  3. 3.0 3.1 "Ashoka Fellow Priscilla Mbarumun Achakpa". Ashoka. Retrieved 2023-09-06. 
  4. "Nigeria Pricilla Achakpa elected as co-facilitator of Women’s Major Group to UNEP – Ecogreen News". Ecogreen News – …Lets make the world greener. 2023-09-06. Retrieved 2023-09-06. 
  5. "Priscilla Achapka Facts for Kids". Kids encyclopedia facts. 2023-07-26. Retrieved 2023-09-06. 
  6. "Dr. Priscilla Achakpa – WEP". WEP – Women Environmental Programme. 2023-09-06. Retrieved 2023-09-06. 
  7. "INTERVIEW: “Gender mainstreaming critical for the success of SDGs in Africa” - Priscilla Achakpa". African Newspage. 2017-12-24. Retrieved 2023-09-06. 
  8. "African Women, Hit Hardest by Climate Change, Forge New Solutions Across the Continent". Democracy Now!. 2015-12-04. Retrieved 2023-09-06. 
  9. "Africa advancing and augmenting the UNFCCC Lima Work Programme on Gender". CCAFS: CGIAR research program on Climate Change, Agriculture and Food Security. 2016-10-06. Archived from the original on 2023-09-06. Retrieved 2023-09-06. 
  10. "Priscilla Achakpa". Women2030. 2023-03-13. Retrieved 2023-09-06. 
  11. David, Rohit (2017-12-05). "Women who have been tortured for the environment". The Economic Times. Retrieved 2023-09-06. 
  12. Nast, Condé (2015-11-30). "Climate Warriors". Vogue. Retrieved 2023-09-06. 
  13. "Vogue Features Women Climate Warriors". WEDO. 2015-12-03. Retrieved 2023-09-06. 
  14. 14.0 14.1 "Meet Priscilla Achakpa, Nigeria". Nobel Women's Initiative. 2018-08-01. Retrieved 2023-09-06.