Proslavery
Ìrísí
Proslavery túmọ̀ sí fífi ọwọ́ sí ìsìnrú.[1] Ìsìnrú jẹ́ ohùn tí àwọn ọ̀jọ̀gbọ́n àtijọ́ míràn fi owó sí, ó sì jẹ́ ohun tí ó farahàn nínú ìwé mímọ́. Àwọn ìwé àkọọ́lẹ̀ Amẹ́ríkà àti Britain àtijọ́ náà tún fọwọ́ sí ìsìnrú, pàápàá jù lọ, àwọn ìwé orílẹ̀ èdè Amẹ́ríkà kí Ìjà abẹ́lé orílẹ̀ èdè Amẹ́ríkà ṣẹlẹ̀. Àwọn kọ̀kan tí ó fọwọ́ sí ìsìnrú ma ń tọ́ka sí Bíbélì mímọ́, wọ́n gbàgbọ́ pé a bí àwọn kọ̀kan láti jẹ́ ẹrú, àwọn míràn sì gbàgbọ́ pé ìsìnrú jẹ́ ohun tí a ti ń ṣe láti ìṣẹ̀báyé.
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ proslavery, collinsdictionary.com