Jump to content

Proturan

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Protura)
Àwòrán Acerentomon

Protura
Ìṣètò onísáyẹ́nsì
Ìjọba:
Ará:
Subphylum:
Ẹgbẹ́:
Ìtò:
Protura

Silvestri, 1907
Families 

Acerentomata

Eosentomata

Sinentomata

Protura, tàbí àwọn proturan, tí ìnagijẹ rẹ̀ ń jẹ́ conehead,[1][2] jẹ́ àwọ́n ẹrankó kékèké (<2 mm ní gígún), tí wọ́n ń gbé inú iyẹ̀pẹ̀, wọ́n kéré tó bẹ́ẹ̀ tí a kò ṣàkíyèsí títí di ogún ọ̀rundún sẹ́yìn.  Protura jẹ́ ẹgbẹ́ àwọn  hexapod tí a kà sí àwon kòkòrò insects, ti a má ań kó wọn sí àyè wọn lọ́tọ̀.[3].

Àwọn ìtọ̣́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "Proturans / Coneheads".
  2. "Order Protura - Coneheads". http://bugguide.net bugguide.net, hosted by Iowa State University Department of Entomology.
  3. Charles S. Henry (2005)