Jump to content

Quincy Jones

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Quincy Jones
Quincy Jones attending an after-party of a tribute to his work at Life Restaurant, Los Angeles, CA on October 1, 2008
Quincy Jones attending an after-party of a tribute to his work at Life Restaurant, Los Angeles, CA on October 1, 2008
Background information
Orúkọ àbísọQuincy Delight Jones, Jr.
Wọ́n tún mọ̀ọ́ bíiLeigh Warren
Ìbẹ̀rẹ̀Seattle, Washington, U.S.
Irú orinPop, funk, soul, big band, swing, jazz, traditional pop, bossa nova, hip-hop
Occupation(s)Musician, conductor, producer, arranger, composer, film composer
InstrumentsTrumpet, drums, vocals, synthesizer
Years active1951 – present
LabelsColumbia, Mercury, Qwest
Associated actsMichael Jackson, Frank Sinatra, Dinah Washington, Dean Martin, Patti Austin, Tevin Campbell, Marvin Gaye, Stevie Wonder, Will Smith
WebsiteOfficial Quincy Jones Website
Jones in 2004 at the World Economic Forum in Davos

Quincy Delight Jones, Jr. (ojoibi March 14, 1933) je ara ile Amerika to je alakoso orin, atokun awo orin, eleto orin, alasopo orin filmu, atokun telifisan, ati afonfere. Larin adota odun to fi sise ninu ise faaji, Jones gba idaloruko fun Ebun Grammy ni igba 79 to je eni akoko to gba eyi,[1] 27 awon Ebun Grammy,[1] ti Ebun Akikanju Grammy ni 1991 je ikan ninu won. O gbajumo gege bi atokun awo orin Thriller, ti Michael Jackson gbe jade ni 1982, eyi to ta iye to je 110 legbegberun kakiriaye,[2] ati atokun ati alakoso orin ore anu “We Are the World”.



  1. 1.0 1.1 Callaway, Sue (2007-01-28). "Fortune test drives a Mercedes Maybach with Quincy Jones — February 5, 2007". Money.cnn.com. Retrieved 2009-07-18. 
  2. "Jacko's Back! | MTV UK". Mtv.co.uk. 2006-11-16. Retrieved 2009-07-18.