Rẹ̀mí Abíọ́lá

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Rẹ̀mí Abíólá
Orílẹ̀-èdèNàìjíríà
Ọmọ orílẹ̀-èdèNàìjíríà
Iṣẹ́
  • actress
  • director
  • producer
Olólùfẹ́Moshood Abiola
Àwọn ọmọ2

Rẹ̀mí Abíọlá tí wọ́n bí ní oṣù Kẹwàá ọdún 1953 tí ó jáde láyé ní oṣù keje ọdún 2009. Jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé, olùgbéré-jáde, ati adarí eré sinimá ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ó jẹ́ ìyàwó Moshood Abíọlá.[1] Rẹ̀mí papò dà ní ọjọ́ kọkàndínlọ́gbọ̀n oṣù kẹjọ ọdún 2009, látàrí àìsàn jẹjẹrẹ tí jákùn ẹ̀mí rẹ̀. Àwọn ọmọ méjì ni ó gbẹ̀yìn olóògbé náà. [2][3][4]

Iṣẹ́ rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Rẹ̀mí kẹ́kọ̀ọ́ nípa eré-oníṣe ní fielding school for dramatic Arts ní ìlú England ní àsìkò ọdún 1970s, lẹ́yìn tí ó fisẹ́ sílẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ònbánisọ̀rọ̀ ní ilé-iṣẹ́ Nigeria Airways. Nígbà tí ó padà sí orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, ó kóp nínú àwọn eré orí ẹrọ amóhù-máwòrán lóríṣirí lábẹ́ àwọn ògbóntagì eléré bíi: Báyọ̀ Àwàlà àti Olóyè Túndé Olóyédé.[5] [6]

3 tún lè wo[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àwọn Ìtókasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àdàkọ:Authority control Àdàkọ:Nigeria-bio-stub