Rabilu Musa
Àdàkọ:Use Nigerian English Àdàkọ:More citations needed
Rabilu Musa | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Danlasan, Kano, Nigeria | 12 Oṣù Kejìlá 1971
Aláìsí | 9 December 2014 Kano, Nigeria | (ọmọ ọdún 42)
Orílẹ̀-èdè | Nàìjíríà |
Ẹ̀kọ́ | Grade II |
Iléẹ̀kọ́ gíga | Government Teachers College Wudil, Kano, Nigeria |
Iṣẹ́ | Òṣèré, Olùgbéré-jáde, ati adarí eré |
Ìgbà iṣẹ́ | 1997–2014 |
Olólùfẹ́ | 3 |
Àwọn ọmọ | 7 |
Awards | See below |
Rabilu Musa, tí gbogbonènìyàn mọ̀ sí Dan Ibro tí wọ́n bí ní ọjọ́ Kejìlá oṣù Kejìlá ọdún 1971, jẹ́ ògbóntagì òṣèré, aláwàdà, olùgbéré-jáde, àti adarí eré Hausa, ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà . Òun ni wọ́n ń pè ní asíwájú ati olùdásílẹ̀ agbo Kannywood , òin náà tún ni ó tún mọ awàdà ṣe jùlọ nínú gbogbo awọn òṣèré aláwàdà ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ṣáájú kí ó papò dà ní ọdún 2014.[1]
Ètò-ẹ̀kọ́ rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Dan Ibro lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ alákòọ́bẹ̀rẹ̀ ti "Danlasan" tí ó wà ní Warawa, ó sì lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ girama "Government Teachers College" tí ó wà ní ìlú Wudil ní Ìpínlẹ̀ Kánò. Ó dara pọ̀ mọ́ ilé-iṣẹ́ àtúnṣe awọn ẹlẹ́wọ̀n ní ọdún 1991, tí ó sì fisẹ́ náà sílẹ̀ ní lẹ́yìn ọdún díẹ̀, láti dara pọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ òṣèré tíátà. Eré rẹ̀ akọ́kọ́ tí ó kọ́kọ́ gbé jáde ni 'Yar Mai Ganye which promoted his career.[citation needed]
Popular songs include Bayanin Naira, Idi Wanzami, Dureba Makaho.[citation needed]
Early career
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Rabilu Musa became popular in Hausa movie cinema few years after when he joined the industry. Some of his popular movies includes Andamali, Ibro Aloko, Ibro Angon Hajiya, Ibro Dan Fulani. His career as an actor continues when he turned to be a full-time comedian and began singing with his popular songs such as Bayanin Naira, Idi Wanzami, Direba Makaho.[2]
Àwọn àṣàyàn eré rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]↓ Eré | Ọdún |
---|---|
'Yar Mai Ganye | ND |
A Cuci Maza | 2013 |
Akasa Atsare | 2011 |
Allo | ND |
Andamali | 2013 |
Bita Zai Zai | ND |
Borin Ibro | ND |
Dan Auta Amalala | ND |
Dan Gatan Ibro | ND |
Dawa Dai | ND |
Gabar Ibro | ND |
Ibro Alkali | 2012 |
Ibro Aloko | 2007 |
Ibro Angon Hajiya | ND |
Ibro Ba Sulhu | 2014 |
Ibro Dan Almajiri | ND |
Ibro Dan Chacha | ND |
Ibro Dan Daudu | 2011 |
Ibro Dan Fulani | ND |
Ibro Dan Nageriya | ND |
Ibro Dan Polio | ND |
Ibro Dan Siyasa | ND |
Ibro Dan Zaki | ND |
Ibro Dawo-Dawo | 2011 |
Ibro Mahaukaci | ND |
Ibro Mai Babbar Riga | ND |
Ibro Police | ND |
Ibro Producer | 2011 |
Ibro Saye da Sayarwa | ND |
Ibro Sudan | ND |
Ibro Wuju Wuju Basu | 2011 |
Ibro Ya Auri Baturiya | 2010 |
Kankamba | ND |
Karfen Nasara | 2015 |
Kaso | ND |
Kowa Yabi | ND |
Mahauta da Fulani | ND |
Mai Dalilin Aure (Match Maker) | 2014 |
Maidaben Bagi | ND |
Mazan Baci | ND |
Namamajo | ND |
Ragon Shiri | ND |
So Kasheni | ND |
Sukuni | ND |
Tun Ran Gini | ND |
Uwar Gulma (The Mother of Gossip) | 2015 |
Awards
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Year | Award | Category | Film | Result |
---|---|---|---|---|
2014 | 2014 Nigeria Entertainment Awards | Best Supporting Actor | Special Recognition | Yàán |
2015 | 2nd Kannywood/MTN Awards | Best Comedian (Jurors Choice Awards) | Posthumous Award[3] | Gbàá |
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Comedian ‘Dan Ibro’ buried in Kano". Premium Times Nigeria. 2014-12-10. Retrieved 2020-11-18.
- ↑ "Best of Rabilu Musa Dan Ibro for Android - APK Download". APKPure.com. 2018-05-25. Retrieved 2020-11-18.
- ↑ Lere, Mohammed (1 February 2015). "Late Ibro honoured at MTN Kannywood Awards 2015". Nigeria: Premium Times. Retrieved 18 May 2020.
- Pages with script errors
- All articles with unsourced statements
- Articles with unsourced statements from May 2020
- Articles with invalid date parameter in template
- Àwọn ọjọ́ìbí ní 1971
- Àwọn ọjọ́aláìsí ní 2014
- Nigerian male film actors
- Hausa-language mass media
- Male actors in Hausa cinema
- 21st-century Nigerian male actors
- People from Kano State