Rachael Yamala
Ìrísí
Personal information | |||
---|---|---|---|
Ọjọ́ ìbí | 12 Oṣù Kejì 1975 | ||
Playing position | Midfielder | ||
Senior career* | |||
Years | Team | Apps† | (Gls)† |
Kakanfo Babes | |||
National team‡ | |||
Nigeria women's national football team | |||
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only. † Appearances (Goals). |
Rachael Yamala jẹ agbàbọọlu lobinrin orilẹ ede Naigiria ti a bini 12, óṣu Febuary ni ọdun 1975. Arabinrin naa ṣere gẹgẹbi midfielder fun team awọn obinrin naigiria ti national lori bọọlu[1].
Àṣèyọri
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Arabinrin naa wa lara ọkan ninu team Cup FIFA awọn obinrin àgbaye ni ọdun 1991[2].