Rafeal Pereira Da Silva

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Rafael Pereira da Silva

Rafeal Pereira da Silva (a bi ni ọjọ kẹsan oṣù keje ọdún 1990) jẹ ọmọ orílẹ̀-èdè Brasil, iṣẹ́ bọọlu afẹsẹgba lọ n ṣe. O tún gbà bọọlu fún ikọ Manchester United ní orílẹ̀-èdè England.

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]