Rahila Hadea Cudjoe

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Ìwé-alàyé[ìdá]
Rahila Hadea Cudjoe OFR
Chief Judge of Kaduna State
In office
1996–2014
AsíwájúJustice Saka Adeyemi Ibiyeye
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí6 Oṣù Kẹ̀wá 1948 (1948-10-06) (ọmọ ọdún 75)
Zaria, Kaduna State, Nigeria
Alma materAhmadu Bello University
Occupation

Justice Rahila Hadea Cudjoe OFR (ọjọ́ ìbí Jésù ojọ́ kẹfà osù kẹwàá, ọdún 1948) jẹ́ Onísòfin kan ri to àti Adájọ Àgbà kan ri ni ìpínlè Kaduna. O jẹ́ Obìnrin Àkọkọ́ láti dé ipò Adájọ Àgbà ní ìpínlè Kaduna tí ó sì ṣe ìsìn láti ọdún 1996 títí dé ọdún 2014.[1] Ó tún jẹ́ Agbẹjọ́rò Obìnrin àkọkọ́ ní North Western State àti Obìnrin àkọkọ́ tí ó jẹ́ agbẹjọ́rò òfin ní ìpínlẹ̀ Kaduna.[2][3]

Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀ Ìgbé Ayé àti Iṣẹ́[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Adájọ Àgbà Rahila jẹ́ ọmọ bíbí ile Sáríà ní ìpínlè Kaduna tí wọn bí ní ọdún 1948. Ó lọsí ilé ìwé Alákọ́bẹ̀rẹ̀ tí orúko rè ń jẹ́ Our Ladies High School ní Kaduna àti ilé ìwé gíga tí Ìjọba Government Girls College ní Dala ní ìpínlè Kano, lẹ́yìn èyí ní ó wà lọsí Fásitì tí ó tí lọ kà nípa Òfin ní Fásitì Ahmadu Bello ní Ìpínlè Zaria. Rahila léyìn èyí ní wọn pè sí Nigerian Bar Schools ní ọdún 1973.[2]

Iṣé[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Rahila bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ òfin rẹ̀ gẹ́gẹ́ bi Olùdámọ̀ràn Ìlú ní Ilé-iṣẹ́ Ìdájọ ti Ìpínlè Kaduna. Ní ọdún 1979, wọ́n tún yàn gẹ́gẹ́ bí ẹni tí yóò jẹ́ Draftsman Òfin ti awọn Ministry of Justice ní Ìpínlè Kaduna àti Olùdámọ̀ràn Òfin sí ilé ìgbìmò aṣòfin tí Ìpínlè Kaduna ní 1983, lẹ́yìn èyí ní wọn yán-àn gẹ́gẹ́ bí Adájọ́ fún ilé-ẹjọ́ Gíga tí ìpínlè Kaduna.[4] Lábẹ́ ìdarí Gómìnà Àná ti orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Lawal Laiya tí ìpínlè Kaduna ni won tí yan Rahila gẹ́gẹ́ bí Adájọ́ Àgbà fún ìpínlè náà. Ó jẹ́ olókìkí àti gbajúmò fún ìdarí ìṣẹ̀lẹ̀ tí ojà Zangon Kataf, lábẹ Ìgbìmọ̀ Ìdájọ Riots tí Ipinle Kaduna ní ọdún 1992.[5][2]

Àwọn ibì tí ó ti ń ṣe Ẹgbẹ́[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ẹwo àwọn mìíràn[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Book on Justice Cudjoe for presentation". Latest Nigeria News, Nigerian Newspapers, Politics (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2013-12-16. Retrieved 2020-11-21. 
  2. 2.0 2.1 2.2 Admin (2017-02-07). "CUDJOE, Rahila Hadea". Biographical Legacy and Research Foundation (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-11-21. 
  3. Commonwealth Judicial Education Institute Report, Prof. N.R. Madhava Menon (2013). "Newsletter of the Commonwealth Judicial Education Institute". Commonwealth Judicial Education Institute. http://cjei.org/publications/Fall%20Newsletter%202013.pdf. 
  4. Federal Republic of Nigeria - Official Gazette (1988). APPOINTMENT OF JUDGES.. Lagos: The Federal Government of Nigeria. pp. 181. 
  5. Nwadinobi and Maguire, Eleanor Ann and Sarah (2013). THE ROLE OF WOMEN AND GIRLS IN PEACE INITIATIVES IN NIGERIA. Nigerian Stability and Reconciliation programme. pp. 3.1 and 3.2.1.