Raphael Saadiq
Ìrísí
Raphael Saadiq | |
---|---|
Saadiq at the 2012 Time 100 | |
Background information | |
Orúkọ àbísọ | Charles Ray Wiggins |
Ọjọ́ìbí | 14 Oṣù Kàrún 1966 |
Ìbẹ̀rẹ̀ | Oakland, California, U.S. |
Irú orin | |
Occupation(s) |
|
Instruments |
|
Years active | 1983–present |
Labels | |
Associated acts | |
Website | raphaelsaadiqmusic.com |
Raphael Saadiq ( /səˈdiːk/; orúkọ àbísọ Charles Ray Wiggins; May 14, 1966) ni akọrin, akọ̀wé-orin, onílù-orin, àti olóòtú àwo-orin ará Amẹ́ríkà. Ó gbajúmọ̀ bíi ọ̀kan nínú ọmọ ẹgbẹ́ olọ́rin Tony! Toni! Toné!. Ó ti ṣe olóòtú orin fún àwọn akọrin míràn bíi Joss Stone, D'Angelo, TLC, En Vogue, Kelis, Mary J. Blige, Ledisi, Whitney Houston, Solange Knowles àti John Legend.