Razaq Olayiwola
Ìrísí
Razaq Olayiwola tí orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ ń jẹ́ Òjòpagogo jẹ́ Gbajúmọ̀ òṣèré ọmọ bíbí orílẹ̀ èdè Nàìjíríà. [1] Òun ni ọkọ gbajúgbajà òṣèrébìnrin sinimá àgbéléwò, Mojí Afọláyan.
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "See Olayiwola Razaq Ojopagogo Profile and Image Collections on PicsArt". PicsArt. Retrieved 2019-12-31.