Razia Sultan (Sinimá àgbéléwò)
Razia Sultan | |
---|---|
Fáìlì:Razia Sultan serial poster.jpg Promotional image for Razia Sultan | |
Genre | Historical Drama |
Created by | Siddarth Kumar Tewary |
Written by | Anshuman Sinha Surabhi Saral Saba Mumtaz |
Directed by | Mukesh kumar singh Arif Ali Ansari Hasnain Haiderabadwala Manish Singh Kamal Monga |
Creative director(s) | Prakriti Mukherjee Amol Soorvey |
Presented by | Swastik Pictures |
Starring | See Below |
Country of origin | India |
Original language(s) | Hindi |
No. of seasons | 1 |
No. of episodes | 170 |
Production | |
Producer(s) | Siddarth Kumar Tewary Gayatri Gill Tewary Rahul Kumar Tewary |
Production location(s) | India |
Editor(s) | Paresh Shah Ayan B Hashmi |
Camera setup | Multi-camera |
Running time | Approx. 22 minutes |
Production company(s) | Swastik Pictures |
Release | |
Original network | &TV |
Picture format | 576i (SDTV) |
Original release | 2 Oṣù Kẹta 2015 | – Oṣù Kẹ̀wá 23, 2015
External links | |
Website |
Razia Sultan jẹ́ Sinimá àgbéléwò orí ẹ̀rọ amóhùnmáwòrán onípele tí wọ́n ṣe àfihàn rẹ̀ bẹ̀rẹ̀ lọ́jọ́ ajé sí ọjọ́ Etì lórí ẹ̀rọ amóhùnmáwòrán &TV[1] láti ọjọ́ kẹfà oṣù kẹta ọdún 2015. Pankhuri Awasthy ni ó kópa olú ẹ̀dá ìtàn náà tí ó ń jẹ́ Razia Sultana. Eré-oníṣe náà dá lórí Razia Sultan (Sultan Razia), obìnrin kan ṣoṣo tí ó jọba ní Delhi Sultanate lórílẹ̀-èdè Indian. Ó dá lórí ọ̀dọ́mọbìnrin kan àti àwọn ìṣòro tí ó dojú kọ ọ́ ní ìgbésí-ayé rẹ̀. Ọ̀gbẹ́ni Shah Rukh Khan ni ó ṣe agbátẹrù eré náà gẹ́gẹ́ bí Sutradhar.[2] Orin tí Supriya Joshi kọ, tí àkọlé rẹ̀ ń Mere Maula ni wọ́n lò nínú sinimá náà.
Kókó ìtàn
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Eré-oníṣe náà dá lórí ìtàn ìgbésí ayé ọmọbìnrin Razia Sultan. Bàbá rẹ̀, Sultan Iltutmish ni ó yàn án ní Àrẹ̀mọ tí ó jọba lẹ́yìn ara rẹ̀, bí ó ti lẹ̀ jẹ́ pé ó ní àwọn ọmọkùnrin púpọ̀, ó gbàgbọ́ pé Razia tó gbangba sùn lọ́yẹ́, tí ó sìn ṣe é fọkàn tán ju àwọn ọmọkùnrin rẹ̀ lọ. She was made the ruler by himself. Eré náà dá lórí akitiyan àti làálàá ojoojúmọ́ Razia gẹ́gẹ́ bí Ọbabìnrin Indian ní sẹ́ńtúrì kẹtàlá sẹ́yìn.
Àwọn ẹ̀dá-ìtàn
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Pankhuri Awasthy gẹ́gẹ́ bí Razia Sultan
- Rohit Purohit gẹ́gẹ́ bí Ikhtiyar ud-din Malik Altunia
- Saurabh Pandey gẹ́gẹ́ bí Jamal-ud-Din Yaqut
- Sooraj Thapar gẹ́gẹ́ bí Shams-ud-din Iltutmish
- Khalida Turi gẹ́gẹ́ bí Qutub Begum
- Mohit Abrol gẹ́gẹ́ bí Nasiruddin Mahmud
- Seema Kapoor gẹ́gẹ́ bí Shamshad Begum (Valide Sultan)
- Sambhavna Seth gẹ́gẹ́ bí Shah Turkan
- Rishima gẹ́gẹ́ bí Kaneez ti Shah Turkan
- Ankit Arora gẹ́gẹ́ bí Rukn-ud-din Firuz
- Puja Banerjee gẹ́gẹ́ bí ìyàwó Yasmine-Rukn-ud-din Firuz àti ìyá Ala ud din Mausad.
- Zara Barring gẹ́gẹ́ bí Shazia Begum (New Shazia) [3]
- Dalip Tahil gẹ́gẹ́ bí Maroosh
- Manish Khanna gẹ́gẹ́ bí Taj al-Din Yildiz
- Bhavna Chauhan gẹ́gẹ́ bí Shazia Begum (Old Shazia)
- Praneet Bhat gẹ́gẹ́ bí Kasabi Kalandar Lahori / Shagird
- Riya Deepsi gẹ́gẹ́ bí Fatima / Fatima Begum (Validah Sultan)
- Himangini Singh Yadu gẹ́gẹ́ bí Uzma Begum (Old Uzma)
- Jaswinder Gardner gẹ́gẹ́ bí Uzma Begum (New Uzma)
- Swati Anand gẹ́gẹ́ bí Nadira Begum
- Eijaz Khan gẹ́gẹ́ bí Muiz ud din Bahram
- Mandar Jadhav gẹ́gẹ́ bí Iqbal Khan (Tafal Sultan)
- Baizad Khan gẹ́gẹ́ bí Nasir ad-Din Qabacha
- Anil Rastogi gẹ́gẹ́ bí Nizamuddin[4]
- Vikram Sharma gẹ́gẹ́ bí Bilal Khan
- Dhruvee Haldankar gẹ́gẹ́ bí Hippie
- Rishima Sidhu gẹ́gẹ́ bí Kaneez ti Shah Turkan
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Razia Sultan". Archived from the original on 12 February 2015. Retrieved 2015-09-16.
- ↑ "Shah Rukh Khan turns 'sutradhar' for 'Razia Sultan'". Retrieved 16 September 2015.
- ↑ "In & Out: TV celebs onboard, quit or kicked out - The Times of India". Retrieved 16 September 2015.
- ↑ "Veteran actor Dr. Anil Rastogi from Ishaqzaade in &TV's Razia Sultan - Times of India". Retrieved 11 July 2016..