Rita Chikwelu

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Rita Chikwelu
Personal information
OrúkọRita Chikwelu
Ọjọ́ ìbí6 Oṣù Kẹta 1988 (1988-03-06) (ọmọ ọdún 36)
Ibi ọjọ́ibíAsaba, Delta
Ìga160cm
Playing positionForward
Club information
Current clubMadrid CFF
Number18
Youth career
Cold City
Senior career*
YearsTeamApps(Gls)
0000–2005Akwa Starlets
2006–2009FC United Pietarsaari(28)
2010–2016Umeå IK140(16)
2017–2019Kristianstads DFF64(12)
2020–Madrid CFF61(5)
National team
2007–Nigeria women's national football team33(15)
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only and correct as of 00:40, 16 January 2020 (UTC).

† Appearances (Goals).

‡ National team caps and goals correct as of 5 July 2011

Rita Chikwelu jẹ agbàbọọlu lobinrin orilẹ ede Naigiria ti a bini 6, óṣu kẹta ni ọdun 1988. Àrabinrin na ti ṣere fun Club spanish ti madrid CFF atipè o ti fi igba kan ṣere fun Umea IK ati Kristianstads DFF[1].

Àṣeyọri[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  • Chikwelu ti ran órilẹ ède Naigiria lọwọ ninu Cup awọn obinrin ilẹ Afirica ti ere idijè Nations ni ọdun 2016 ati 2018. Atipe o tun kopa ninu Cup awọn obinrin agbaye[2][3][4]

Itọkasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Ẹda pamosi". Archived from the original on 2022-05-18. Retrieved 2022-05-28. 
  2. https://www.foxsports.com/soccer/fifa-womens-world-cup/rita-chikwelu-player
  3. "Ẹda pamosi". Archived from the original on 2022-05-28. Retrieved 2022-05-28. 
  4. https://www.premiumtimesng.com/sports/football/334007-norway-vs-nigeria-live-updates-super-falcons-seek-bright-start-in-womens-world-cup.html