Rita Nwadike
Ìrísí
Personal information | |||
---|---|---|---|
Ọjọ́ ìbí | 3 Oṣù Kọkànlá 1974 | ||
Ibi ọjọ́ibí | Nigeria | ||
Ìga | 1.54m | ||
Playing position | Midfielder | ||
Senior career* | |||
Years | Team | Apps† | (Gls)† |
2004 | Rivers Angels | ||
National team | |||
2004 | Nigeria women's national football team | 14 | (0) |
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only. † Appearances (Goals). |
Rita Nwadike jẹ ọkan lara awọn agbabọọlu lobinrin orilẹ ede Naigiria tẹlẹ ti a bini 3, óṣu November ni ọdun 1974. Àrabinrin naa ti ṣere fun team awọn agbabọọlu Obirin Naigiri ti national ni olympic ọdun 2004[1].
Aṣeyọri
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Rita lo kọkọ scorẹ goal fun órilẹ ede Naigiri ni Cup FIFA awọn obinrin agbaye ninu idije to waye ni sweden ni ọdun 1995[2][3].
- Rita ati awọn akẹgbẹ rẹ kopa ninu quarter finals ti Cup FIFA awọn obinrin agbaye to waye ni ilẹ america ni ọdun 1999, lẹyin ọdun mejilelogun ni awọn elere yii gba ami ẹyẹ fun àṣeyọri naa to waye ni Victoria Island ni ilu Eko[4][5].
Itọkasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ https://www.eurosport.com/football/rita-nwadike_prs414602/person.shtml
- ↑ https://www.fifa.com/tournaments/womens/womensworldcup/sweden1995/teams/1882893
- ↑ "Ẹda pamosi". Archived from the original on 2021-05-06. Retrieved 2022-05-26.
- ↑ https://www.thisdaylive.com/index.php/2021/09/20/22-years-after-nff-to-honour-super-falcons-class-of-1999/
- ↑ https://thewillnigeria.com/news/nff-honours-super-falcons-class-of-1999-at-nff-aiteo-awards-ceremony/