Rita Orji
Ìrísí
Rita Oluchi Orji jẹ́ ọmọ orílé-èdè Nàìjíríà, tí ó tún fi apá kan tan mọ́ Canada. Ó jẹ́ onímọ̀ kọ̀m̀pútà fún Kánádà nínú ìwádìí jinlẹ̀ fún ẹgbẹ́ pasuáfùù. Àti olùdarí pasuáfùù kòmpútí laàbù tí ilé ẹ̀kọ́ gíga yunifásítì Dalhousie.[1] Ìṣe rẹ̀ dá lé lórí bí a ṣe lè lo ìṣòro ǹ gbésì láàrin ènìyàn àti ẹ̀rọ kọ̀m̀pútà.
Ó ti gbá àmì ẹ̀yẹ tó ti tó àádọ́rin, àti àmì ìdánimọ̀ ní agbègbè, àyíká àti àgbà-ń-lá-ayé. Ó sì tún ṣe iṣẹ́ pàtàkì nípa rírí sí àsíá àwọn obìnrin nínú ẹgbẹ́ Àjọ àwọn Orílẹ̀-èdè panel, tí ilé ìgbìmò asòfin Kánádà.[2]
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedFCS
- ↑ "Rita Orji | McGill University - Academia.edu". mcgill.academia.edu. Retrieved 2020-05-24.