Roald Amundsen
Appearance
Roald Engelbregt Gravning Amundsen | |
---|---|
Roald Engelbregt Gravning Amundsen | |
Ọjọ́ìbí | Borge, Østfold, Norway | 16 Oṣù Keje 1872
Aláìsí | c. 18 June 1928 (ọmọ ọdún 55) unknown |
Iṣẹ́ | Explorer |
Parent(s) | Jens Amundsen, Hanna Sahlqvist |
Roald Engelbregt Gravning Amundsen (Àdàkọ:IPA-sv; 16 July 1872 – c. 18 June 1928) je oniwakiri ara Norway. ọmọ ọdún márùn dín ní ọgọ́ta ni. Ẹni àkọ́kọ́ tí ó dé póólù gúsù. Ó ṣe alábápàdá ikú rẹ̀ ní ibi ìjàmbá ọkọ̀ òfurufú ní odò bárẹ́ǹtì. Àwon òbí rẹ ni Jen Amundsen àti Hanna Sahlqvist. Ó gba àmì ẹ̀yẹ Úbádì ní ọdún 1907 láti ọwọ àwọn Ẹgbẹ arin ìrìn àjò aláwárí fún eni àkókó tí ó ṣe àwárí agbègbè Àríwá ìlà oòrùn. Kò gbè ìyàwó, bẹ́ẹ́ní kò sì bí omo.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |