Robert Adam

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Robert Adam

Portrait attributed to George Willison, c. 1770-75
Personal information
Name Robert Adam
Nationality Scottish
Birth date 3 July 1728
Birth place Kirkcaldy, Fife [1]
Date of death 3 March 1792 (Aged 63)
Place of death London
Work
Buildings Syon House
Culzean Castle
Kedleston Hall
Pulteney Bridge

Robert Adam Wọ́n bí Adam ní 1728. Ó kú ní 1792. Yaléyalé (architect) ni. Ọmọ ilẹ̀ Scotland ni. Ọkùnrin mẹ́rin ni àwọn òbí rẹ̀ bí. Ó jẹ́ ọkan nínú wọn. Díẹ̀ lára àwọn ilé tí ó yà ni Harewood House, York; Osterley Park, Kedleston Hall, Derbyslire; Luton Hoo, Bedfordshire àti Kenwood.


  1. Civic Society Kirkcaldy:A History and Celebration p. 60.