Rodney Joseph Johnson
Rodney Joseph Johnson (October 24, 1965 - September 21, 2006) jẹ́ agbófin ró lábé ilé iṣé ̣ọlọ́pàá Houston. Ẹni tí ó lo ọdú mẹ́rìnlá (14 years) pẹ̀lú ilé iṣẹ́ nàà ṣáajú ìpapòdà rẹ̀ lẹ́nu iṣẹ́ ni ́ọjọ̣́ kọ̣kànlé-lógún oṣù kẹ̣́jọ, ọdún 2006.
Juan Leonardo Quintero tó jẹ́ ẹni tó gbònà àìtọ́ wọ ilẹ̀ [[Mexico]] lẹ́yìn tí wọ́n ti le kúrò ní ilẹ̀ [[America]] fún èsù ìfipá-báni lòpọ̀ tí ó hù sí ọmọbìnrin kan ṣùgbọ tí ó padà wọ ilú náà ó gbìyànjú láti dojú èsùn tí wọ́n fi kàn án "tí wọ́n sì fi sílẹ̀ lẹ́yìn tí ìwé ìròyìn gbe wì́pé ó ní àrùn ọpọlọ kan. "[1][2][3] ní ọ̀dún 2008, Wọ́n dájọ́ ẹ̀wọ̀n gbére life imprisonment fún Quintero fún ìwà ọ̀daràn rẹ̀ náà.[4]
Ìbẹ̀rẹ̀ Ìgbésí ayé rè
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Wọ̣́n bí Rodney Johnson ní ọjọ́ karùndínọ́gbọ̀n oṣù kẹ́sàán, ọdún 1965 (October 25, 1965) sí ìdílé David E. Johnson àti Cynthia Johnson nílùú Houston, [[Texas]]. Ní déédé ọmọ ọdún mẹ́rìnlá (age 14), Johnson lọ sí [[Oakland]], ìpínlẹ̀ [[California]] ó kàwé ní ilé-ìwé gíga ti Oakland Technical High School ó sì kẹ́kọ̀ọ́ gboyè ní ọdún 1984. lẹ́yìn tí ó kàwé-gboyè tán, ó forúkọ sílẹ̀ láti dara pọ̀ mọ́ ọmọ ogun ilẹ̀ Amẹ́ríkà U.S. tí ó sì sin ilẹ̀ baba rẹ̀ fún ọdún mẹ́fà gbáko.
Ìtàn iṣẹ́ agbófinró rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Johnson sin ilẹ̀ baba rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ọlọ́pàá ọmọ ogun military policeman nínú ọmọ-ogun U.S. àti gẹ́gẹ́ bí ẹni tí ó ma ń ṣàtúnṣe sí ìwà ọ̀daràn nílé iṣẹ́ ọlọ́pàá Texas Department of Criminal Justice ṣáájú kí ó tó dara pọ̀ mọ́ ilé-iṣẹ́ ọlọ́pàá Houston Police Department ní 1994. Wọ́n fun ní àmì ẹ̀yẹ ẹni tí ó ma ń gba ẹ̀mí ará ìlú là jùlo láti ilé iṣẹ́ ọlọ́pàá Houston Police Department àti àmì ẹ̀yẹ akínkanjú ní Texas bákan náà fún iṣ́e tí ó ṣe ní Southeast Gang Task Force. Lẹ́yìn tí ó sin Southeast Gang Task Force tán, wọ́n gbe lọ sí Traffic Division, ní ibi tí ó ti fẹ́ràn iṣẹ́ tí ó tún ṣe síi gidi-gidi. Ìyàwó rẹ̀, Joslyn Johnson náà tún jẹ́ Sergeant ní ilé iṣẹ́ ọlọ́pàá Houston.
Iṣẹ́ tí ́ ṣe kẹ́yìn kó tó kú
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ni ojo kokanle-logbo osu kesan, odun 2006 (September 21, 2006,) Johnson gan ni oko ti o n sare asapajude kan ni iwon 50 MPH si 30 MPH ni opopona Randolph nitosi Braniff, ti o un sumo William P. Hobby Airport southeast ti downtown. oko ti8 o sare asa-pajude yii je oko Olopon-Foodu (Ford pickup truck) ni eyi ti o je pe Juan Leonardo Quintero lo waa. Johnson da oko naa duro, ti o si beere fun iwe-awako Quintero ni eyi ti. Quintero ko le mu jade fun idanimo. Jhonson ba kuku mu ti o si fi mamu-gaari si lowo, o tii sinu oko agbofinro re, o ti lekun mo. lati ko iwe ijabe-esun lolri Quintero. Nibi ti Jhonson ti n se eyi lowo ni Quintero ti ra pala yi owo re pada siwaju toun ti mamu-gaari owo re, ti o si mu ibon ilewo kan 9MM caliber handgun ti o so mo okun idi re ti o si yiin fun olopaa Johnson, amo ki Jhonson to ku, o gbiyanju lati te ero ipe paja-wiri ti o wa nibi oko re, ni eyi ti o sofofo fun ile-ise olopaa wipe olopaa kan wa ninu idaanmu lowo lowo. leyin ti Quintero yinbon lu Johnson tan, o tun yinbon ti oko eso oju popo to wa nitosi ibe sugbon o tase. Nigba ti awon olopaa to ku debe, won ba Quintero leni ti o si jokoo seyin oko ti Jhons fi si tou ti mamu-gaari owo re pelu ibo t mu dani. Won si fi Quintero si ahamo rtin igba naa.
Ìsìnkú àti ìṣẹ̀yẹ ẹni rere
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ojo ketadinogun osu kesan odun 2006 (September 27, 2006) ni won sin Johnson. O le ni egberun merin eniyan ti o wa sibi ayeye isinku oloogbe naa, yato si laami-laaka ninu ise olopaa ni ipinle naa [5] idawo jo po ti o le ni $87,000 ni won da jo fun iese olopaa ologbee naa. Ti egbe (organization for family members of fallen firefighters and police officers) naa si tun seye tiwon naa fun..
Olola-julo ti ipinle Texas iye Rick Perry naa da Jhonson lola pelu ami eye ti 'Star of Texas Award', eyi ti won ma n fun akoni agbofinro toba ku senu ise re, koda awon omo ile igbimo asofin agba ti ipinle Texas.[6] The Texas Senate naa tun fun ni ami eye idani-lola.[7]
Ìpẹ̀jọ́ Opó
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Iyawo Johnson ti oruko re n je Joslyn pe ejo meri otooto leyin iku oko re.[8] ni odun 2008, o pe ilese olopaa ti oko re sise keyin lejo wipe iyen Houston Police Department fun 'Iku Aito' atari wipe ile ise olopaa naa pe won ko gba olopaa meji laye ati sise po.[9] Ni eyi ti won da opo ninu ejo naa nu. Ekeji ni pipe aajo Houston lejo lori ' Ikuna lori ifito ilesse awon olopaa oju popo leti oruko awon arufin eto irin-ajo towo awon agbofinro to n ri si eto iwolewode arinrin-ajo ni ipine naa' ti o si bu enu ate lu wipe ko bofin mu. Ni 2010, won da ejo yii nu ni ile ejo apapo kan ti o n je federal district court ti won sin so wipe ejo naa ti fara pe ejo akoko ju. Ni 2011, bakan naa, U.S. Court of Appeals for the Fifth Circuit sayi pada lori ero won pelu iwadi wipe " esun Joslyn Jhonson tako opo ninu ofin ti won iyen 'HPD' ni eyi to sokufa iku ogbeni Rodney Jhonson."
Ọ̀daràn
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Juan Leonardo Quintero, ti o je omo marundinlogoji (35), ni o je arinrin-ajo lona ti ko bofin mu, ti o si tun ni akosile wipe o ni arun opolo atari isubu re latigba ewe re.[10] Quintero koko wo U.S. ni odun 1994, lona aibofinmu nipa da Matamoros koja ti o si Houston. Won tun mu ni 1995 fun iwa omuti para, bakan naa ni won tun m fun wiwa oko pelu iwe idanimo ti won fura si ni 1996. NI odun 1998, o bebe fun idariji lori iwa aito to hu si omode-binrin omo odun mejia (12)kan pelu ki won ba poun fowo eo ejo naa seyin. Ni April 1999, won tii mole fun rirufin irina, ti won si da pada si Mexico ni osu to te le. Ni opin odun 1999, eni ti o ni okowo landscaping business ti o gba Quintero sise ni Houston ya ni owo pe ki o fi ya oko ka ti won n pe ni coyote pe ki o fi ko fi se fayawo koja ni ibode .
Leyinn ti Quintero yinbo gbemi Johnson, kia ni won ti mu ti wo si fi si ahamo awo olopaa . O bebe pe oun ko moomo paa lati wipe ori ou ko pe rara. Adajo ti o gbo ejo naa ko teti gbo oro enu re, o si dajo ewon gbere fun ni odun 2008. Ewe, o btun je okan lara awon ti owo te lasiko ti won gbiyanju lati sa jade ni ogba ewon Allan B. Polunsky Unit, ogba ewon ti o wa ni Livingston, Texas, ni odun 2010.[11]
Ṣíṣe ìdájọ́ agbódegbà ọ̀daràn náà
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ni odun 2009, Robert Lane Camp, eni ti o ni ilese landscaping ti o gba Quintero sise, ti o si ya nile gbe jewo pe looto ni oun jebi esun ti ijoba fi kan oun pe oun gba alejo aito to wolu lona aito sile ti ou si raan lowlo lati huwa odaran sugbon ki ioba dakun-dabo ki won fowo wonu dariji oun ni ile-ejo U.S. District Court for the Southern District of Texas. Ni odun 2010 ni won da Camp lejo ewon osu meta pere ninu ie ara re( home confinement), ti won si tun fi si abe iso awo lopaa fu odidi oduo marun. Eleyii yoo je gege bi ijiya ati ikilo fun enikeni ti o ba tun gba alejo to wolu lona aito gege bi oun ti [12] U.S. Attorney Don DeGabrielle so ni Houston .[13]
Àwọn ìtọ́ka sí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Jay Root, After Deportation, Killer Returned Easily to U.S., Texas Tribune (February 11, 2016).
- ↑ "Cop Killing Sparks Immigration Debate: Police Chief Blames Federal Government for Officer's Death". ABC News. Retrieved 2010-04-03.
- ↑ James C. McKinley, Jr. (2009-07-25). "Both Sides Find Fault With Effort to Deport Immigrants". The New York Times. Retrieved 2010-04-03.
- ↑ Brian Rogers & Dale Lezon, Jurors sentence HPD officer's killer to life, Houston Chronicle (May 20, 2008).
- ↑ "Thousands Honor Slain Officer At Memorial". KPRC Houston. 2006-09-27. Archived from the original on 2010-09-10. Retrieved 2010-04-03.
- ↑ "Gov. Perry Honors Texas' Fallen and Injured First Responders with Star of Texas Awards". Office of the Governor of Texas, Rick Perry. Retrieved 2010-04-03.
- ↑ "SR 912, 80th Regular Session: In memory of Rodney Joseph Johnson". Texas Legislative Reference Library.
- ↑ Cindy George, HPD widow's suit against city revived, Houston Chronicle (September 9, 2011).
- ↑ Chris Vogel (2008-09-24). "Slain HPD Officer's Wife Sues Over One-Cop-Per-Car Policy". Houston Press. Archived from the original on 2008-09-25. Retrieved 2010-04-03.
- ↑ Mary Benton (2008-05-08). "Immigrant Found Guilty Of Killing Officer". KPRC Houston. Archived from the original on June 13, 2008. Retrieved 2010-04-03.
- ↑ "Cop killer in alleged prison escape try". United Press International. Retrieved 2010-04-03.
- ↑ "Business Owner Convicted of Harboring an Illegal Alien Sentenced" (Press release). United States Attorney's Office for Southern District of Texas. May 10, 2010.
- ↑ "Employer of suspect in officer's death arrested: Prosecutors say illegal immigrant charged in killing of officer got help to re-enter U.S.". Houston Chronicle. Retrieved 2010-04-03.