Jump to content

Roger Sherman

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Roger Sherman

Roger Sherman jẹ́ ọ̀kan pàtàkì nínú àwọn adarí àti Agbẹjọ́rò tí ó sì jẹ́ ẹni tí ó da ilẹ̀ United States sílẹ̀ .[1] Òun ni ẹni ákọ́kọ́ tí ó kọ́kọ́ fọwọ́ bọ̀wé ìfilọ́ọ́lẹ̀ àkójọpọ̀ ilẹ̀ Amẹ́ríkàUnited States, Òun náà ló tún kéde ìgbòmìnira orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà , pàá pàá jùlọ ṣíṣàgbékalẹ̀ ọ̀kan-ò-jọ̀kan ìlànà àti òfin orílẹ̀-èdè olómìnira Amẹ́ríkà. [2][3]

Àwọn Ìtaọ́ka sí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Signers of the Declaration of Independence: Roger Sherman". US History. 1995-07-04. Retrieved 2019-10-27. 
  2. "Roger Sherman". Encyclopedia Britannica. Retrieved 2019-10-27. 
  3. "Roger Sherman". Biography. 2014-04-02. Retrieved 2019-10-27.