Jump to content

Ronald Chagoury (Oníṣòwò)

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Ronald Chagoury
Ọjọ́ìbí8 Oṣù Kínní 1949 (1949-01-08) (ọmọ ọdún 75)
Benin City, Nigeria
Orílẹ̀-èdèNigerian
Ẹ̀kọ́College des Frères Chrétiens des Écoles Chrétiennes
Iléẹ̀kọ́ gígaCalifornia State University, Long Beach
Iṣẹ́CEO, Chagoury Group
Parent(s)Ramez and Alice Chagoury
Àwọn olùbátanGilbert Chagoury (brother)

Ronald Chagoury (ọjọ ìbí Jésù ọjọ kẹjọ, oṣù kínní ọdún 1949) jẹ́ Oníṣòwò kàn ní orílé èdè Nàìjíríà, òun àti àbúrò rẹ̀ Gilbert Chagoury ní wọn jọ dá ilé iṣé Chagoury Groupb sílẹ, wọn sì jọ jẹ Olùdarí àti Olúdàsìlè.

Wọn bí Ronald Chagoury sí orílè èdè Nàìjíríà ní ọjọ́ kẹjọ oṣù kínní ọdún 1949, tí ó jẹ́ ọmọ Ramez àti Alice Chagoury, tí wọ́n dì jọ kúrò ní Lebanon ní ọdún 1949. Ó kàwé ní College des Frères Chrétiens ní Lebanon, bákan náà ní ọ kàwé gbọye nínú èkó ìṣirò ni Fásitì ti ó wà California ní Long Beach ní orílé èdè Améríkà.[1]

Chagoury ṣe ìgbéyàwó pẹlu Berthe, wọn sì jọ́ bímọ méjì.[1]

Orúkọ Chagoury'l tí jáde nínú ìwé ìròyìn Panama.[2]

  1. 1.0 1.1 "Executive Team". Chagoury Group. Archived from the original on 2016-05-22. Retrieved 2016-05-20. 
  2. Leaf, Aaron. "Nigeria's Chagoury Group Named In Latest Panama Papers Revelation Okayafrica". Okayafrica.com. Retrieved 2016-05-20. 

Àdàkọ:Authority control


Àdàkọ:Nigeria-business-bio-stub